Fidio: Itan Igbesi Aye Obafẹmi Awolọwọ Ori Kẹta (Apa Kin-in-ni)

ki o le je ẹkọ fun ọmọ Yoruba gbogbo. Ọdun 2019 ni a ti tẹ iwe yii jade pẹlu aṣẹ lati ọdọ Obafẹmi Awolọwọ Foundation, labẹ akoso Ambassador Tokunbo Awolọwo-Dosumu. Budo Agbaye to n ri si Iṣẹ-Ọna ati aṣa Yoruba (Internationa Centre For Yoruba Arts and Culture) ni Yunifasiti Ibadan lo ni ka ka iwe naa si etigbọọ yin. O ya, ẹ jẹ ka jọ gbadun ẹ.

 

Leave a Reply