Fidio: Iya ẹni ọdun mejidinlogoji to pada sileewe girama niluu Ilọrin b’ALAROYE sọrọ

Ko sigba teeyan daṣọ ti ko ri i fi wọlẹ. Bẹẹ gẹlẹ lọrọ iya ẹni ọdun mejidinlogoji, Folaṣade Ajayi, to pada sileewe girama niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara. Iya naa ṣalaye pe bi awọn eeyan ṣe maa n kawe, ti wọn si tun n sọ oyinbo lo wu oun lori toun fi pada sileewe.

 

Leave a Reply