FIDIO: Nitori iṣẹlẹ Lekki, awọn ọdọ fi foonu da Tinubu laamu

Awọn ọdọ to n ṣewọde pe Aṣiwaju Tinubu lori foonu lati fẹhonu wọn han.

Loootọ lo ba wọn sọrọ, ṣugbọn ọkunrin naa ko si ni Naijiria ba a ṣe n sọ yii. Alẹ ana lo filu silẹ lọ sorileede Faranse.

FIDIO:

Leave a Reply