Gomina Kaduna nigba kan, Balarabe Musa ti ku o!

Gomina ipinlẹ Kaduna telẹ, Alaaji Balarabe Musa ti ku o.

Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni baba naa jade laye nile rẹ niluu Kaduna, lẹni ọdun mẹrinlelọgọrin.

Sẹnetọ Sheu Sanni toun naa jẹ ọmọ bibi ipinlẹ Kaduna lo fi ọrọ yii lede lori ẹrọ abẹyẹfo re, twitter.

 

Leave a Reply