Ija buruku n ṣẹlẹ lagbegbe Owode si Mile 12, l’Ekoo

Aderohunmu Kazeem

Wahala buruku lo n ṣẹlẹ lọwọ bayii lagbegbe Owode si Mile 12 l’Ekoo.

Wọn ni bi wọn ṣe n ba motọ jẹ, bẹẹ ni wọn n fọ ṣọọbu kiri.

ALAROYE gbọ pe niṣe lawọn eeyan n fi mọto wọn silẹ, ti kaluku si bẹrẹ si i sa asala fun ẹmi wọn.

Awọn eeyan ti n ke si awọn ẹṣọ agbofinro lati tete waa pana iṣẹlẹ ọhun.

Leave a Reply