Inu Awolọwọ ko le dun lọrun si bi Naijiria ṣe ri loni-in- Tokunbọ Awolọwọ

kan lara awm Oloogbe bafmi Awolwọ, Dokita Ọlatokunbọ Awolọwọ Dosunmu, ti s pe, inu baba oun ko le dun rara plu bi ohun gbogbo e ri ni Naijiria loni-in.

Obinrin to ti figba kan j aoju oril-ede Naijiria loril-ede Netherland yii s pe gbogbo awn ohun ti ijba Awolw mu ni koko iṣẹ idagbasoke pata ni ko si fawọn eeyan lasiko yii, ati pe bi oril-ede yii e ri loni-in, o yat patapata si erongba bafmi Awolw.

Dosumu ni p nnkan ni inu Awolw ko ni i dun si bayii, o ni, e bi igbe aye awn eeyan e ri lasiko yii ni, abi bi awn ohun amayedrun gbogbo ko e si, ti eto iejba paapaa ko dara to. O ni ẹkọ f paapaa ko e deede, bẹẹ gbogbo wa yii naa la gbadun eto kọ-f ti ijba Awolw e, ati pe ayipada nla le de ba gbogbo ohun ta a ka sil yii, ti a ba etan lati e e lna to yẹ.

Ninu r  naa lo ti s pe lara awn eeyan to gbiyanju lati ja fun ominira oril-ede yii ni Ọbafemi n ṣeugbn lj ti a n ṣẹyẹ ominira Naijiria ldun 1960, iwa buruku gbaa ni wn hu si bafmi, nitori ibi ti wn fi aga  si lọjọ naa ku di kaato.

O ni, bo til j pe oun ko ju m dun mkanla l nigba yẹn, sibẹ, bi awn obi oun ti e n s  ninu ile, lyin ayy ominira lọjọ naa fi han pe aaye awn to ti iwọ ninu iṣẹ ijba ni wn to baba oun si, ti iṣẹlẹ naa ko si dun m bi atawọn eeyan ẹ ninu ggẹ bi olori gb alatako to wa. O ni, plu iwa ti wn hu yii, sib, idunnu nla lo jẹ fun Ọbafẹmi pe Naijiria b lw ijba amunisin.

Tokunb Awolw fi kun ọrọ ẹ pe, meloo gan-an la fẹẹ ka ninu ohun rere ti ọkunrin oloṣelu naa ṣe fun ilọsiwaju Naijiria. O ni iwe nla kan wa ti kunrin naa kugbn ede to fi kọ ọ, oun nikan lo ye daadaa, akọle iwe naa si ni, ‘Fun igbe aye rere awn eeyan’ (For the Good of the People). Ṣugbọn ede ti Awolw fi k̀ọ ọ, oun nikan lo mọ itumọ ọrọ to kọ, ko si eyikeyii ninu awọn to n tẹle e to le tumọ ẹ.

Leave a Reply