Iya Gomina Seyi Makinde ti ku o!

Mama Abigael Ọmọjọlagbe  Makinde to jẹ iya Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti jade laye laaarọ yii lẹni ọdun mọkanlelọgọrin.

Awọn oloṣelu atawọn ọtọkulu eeyan lawujọ ni wọn ti n ranṣẹ ibanikẹdun si gomina Ọyọ naa.

Ọjọ kọkanla, oṣu keje, ọdun to kọja, ni mama naa ṣe ajọdun ọgọrin ọdun laye.

One thought on “Iya Gomina Seyi Makinde ti ku o!

  1. Ki Olorun Oba dari gbogbo ese ti mama se laye jiwon ki Olorun si te mama si afefe rere o Amin

    Ki Olorun daabo bo awon omp ati omoomo ti mama fi sile laye o

Leave a Reply