Jẹgẹdẹ yege nile idibo rẹ

Oludije sipo gomina ninu ẹgbẹ PDP, Eyitayọ Jẹgẹdẹ, ti yege ni ile idibo rẹ niluu Akurẹ. Wọọdu keji to wa ni Igbogun/Iṣikan, Ile idibo kẹsan-an, lo ti dibo. Ibo okoolenigba (220) lo ni, nigba ti Akeredolu to n dije lorukọ ẹgbẹ APC ni ibo ọgọta. Ibo meje pere ni Agbọọla ti ZLP ni.

Leave a Reply