Mo ka iyawo mi pẹlu ọkunrin lori bẹẹdi wa, mi o si tori ẹ lu u rara-Fẹmi Fani-Kayọde

O fẹẹ j pe lojoojum ni wahala to wa ninu igbeyawo minisita feto irinna k ofurufu tẹlẹ, Oloye Fmi Fani-Kayde, n fojoojum le si i plu fidio kan to gba igboro kan bayii.

Precious Chikwendu loruk iyawo ẹ yiio si ti to j mta bayii ti awuyewuye ti gbalu pe igbeyawo naa ti fori anpnugbn ti wn kk n dọwo bo o, ki airi bọrọ ọhun ṣe jẹ gan-an too tu sita patapata.

Fidio kan ti ko ju iṣẹju mọkanlelogun lọ nileeṣẹ iwe iroyin kan gbe jade, nibi ti ariyanjiyan kan ti n ṣẹlẹ laaarin Fmi ati iyawo  yii, oju tawn eeyan si fi n wo iṣẹl hun ni pe e ni Fmi n fiya j obinrin naa.

Fmi Fani-Kayde naa ti sr, ori r abẹyẹfo ẹ twitter, lo gba l. Alaye to si e ni pe dk niyawo oun, ori bẹẹdi oun gan-an, nibi tawn ti j n e lkọ-laya lo gbe kunrin kan wa, ti wn j ka m ara wn daadaa nib.

O ni lyin j meloo kan ti iṣẹl hun waye, ti iyawo oun bẹrẹ si i ba gbogbo ile ja, to tun n kanra m awmọ, ti awọn oṣiṣe gan-an ko mọ ohunkohun un ṣe mọ nile loun pe e wi pe ko j ki ogun o sinmi.

Minisita tẹlẹ yii sọ pe nie niyawo oun fa foonu  y, to fẹẹ maa fi kamra r ya oun bi oun ṣe n ba a sọrọ, ti ariyanjiyan si ṣe bẹẹ waye, eyi ti wọn n gbe kiri bayii, bẹẹ ki i ṣe pe oun lu obinrin naa tabi fiya kankan jẹ ẹ.

m mrin lawn tk-taya yii bi funra wn, ninu eyi ti awn ibeta wa ninu  paapaa.

3 thoughts on “Mo ka iyawo mi pẹlu ọkunrin lori bẹẹdi wa, mi o si tori ẹ lu u rara-Fẹmi Fani-Kayọde

Leave a Reply