Nitori Bọde George, wọn fẹẹ da sẹria fun Fayoṣe

Kazeem Aderohunmu

gb oelu PDP l’Ekoo ti fun gomina ipinl Ekiti tl ni gbedeke j meje ko fi tr aforiji lwọ awn agbaagba gb hun, paapaa Alagba Bde Goerge, nitori to sọrọ kobakungbe si i.

Peter Ayọdele Fayoe s lasiko ti gb naa n n ṣe ifilọlẹ eto idibo sileegbimọ aṣofin pe, niṣe lo yẹ ki awọn ọmọ ẹgbẹ PDP Eko fẹyin baba ọhun ti bayii ninu ẹgbẹ.

Fayosọ pe ti ẹgbẹ naa ba fẹẹ laṣeyọri gidi nipinlẹ Eko, afi ki wọn yọwọ Bọde George kuro ninu ọrọ ẹgbẹ oṣelu naa.

r to da wahala sil ree, bẹẹ lẹni to j Alukoro fun gb naa nipinl Eko, gbni Gani Taofeek, ti s pe ọrọ ti Fayoe sọ yii le da gbẹ ru, ati pe o le mu awọn ọdọ kọju oro si Oloye Bọde George, ti nnkan si le ṣe bẹẹ daru mọ ẹgbẹ naa lọwọ nipinlẹ naa.

Wọn ti sọ pe Fayoṣe gbọdọ tọrọ aforiji ni, ti ko ba fẹẹ ki ẹgbẹ da sẹria nla fun oun lori ọrọ yii.

O fi kun un pe ki i ṣe iru asiko ti PDP n palem gidigidi lati gba ipinl Eko m APC lwọ, paapaa fun ipo gomina lọdun 2023, lo y ki Fayoe s r to le tu gb hun ka.

Ni bayii, wọn ti fun un ni ọjọ meje ko fi ṣatunṣe si ohun to ṣe yiibakan naa ni wọn fi kun un pe ti ko ba tọrọ aforiji, ko ni i ltọọ lati kopa ninu eto kankan ti ẹgbẹ ba n ṣenitori kunrin naa ko duro gg bii awokọṣe rere fawd ninu gb naa.

Leave a Reply