O digbooṣe, akọni obinrin wọ kaa ilẹ lọ

Wọn ti sinku Tolulọpẹ Arotile sibi ti wọn maa n sin awọn akọni si ni itẹkuu awọn ologun niluu Abuja. Lẹyin ti wọn ṣẹyẹ ikẹyin loriṣiiriṣii fun un ni wọn gbe e wọ kaa ilẹ lọ.

Adura lawọn eeyan n ṣe pe ki Ọlọrun tu awọn obi rẹ ninu.

Leave a Reply