O ma ṣe o, Akinrun tilu Ikirun ti waja

Florence Babaṣọla

Akinrun tiluu Ikirun, Ọba Rauf Ọlayiwọla Ọlawale, ti waja.

Alẹ Ọjọruu, Wẹsidee, mọjumọ Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii la gbọ pe baba dara pọ mọ awọn baba-nla rẹ.

Ọdun 1990 ni baba yii gun ori itẹ, ileefowopamọ lo si ti n ṣiṣẹ ko too jọba.

Leave a Reply