O ma ṣe o! Eto isinku Tolulọpẹ ti bẹrẹ niluu Abuja

Lọwọlọwọ yii, wọn ti gbe oku ọmọdebinrin to jẹ ẹni akọkọ to n fi baalu-agbera-paa jagun nilẹ wa, Tolulọpẹ Arotile, ẹni ọdun mẹrindinlogun ti wọn pa nifọna-fọnṣu, de itẹkuu awọn ologun to wa loju ọna Papakọ ofurufu ilẹ wa niluu Abuja.

Olori awọn ọmọ ogun ofurufu nilẹ wa, Air Vice Marshal Abubakar Sadique, Gomina ipinlẹ Kogi, Yahya Bello, Alaga igbimọ to n ri si ọrọ ileeṣẹ ofurufu nilẹ wa nileegbimọ aṣoju-ṣofin, Alaaji Ib’ni Nalla, atawọn mọlẹbi Tolulọpẹ ti wa nibi ti wọn ti fẹẹ sinku rẹ.

A oo ma fi to yin leti bo ba ṣe n lọ.

Leave a Reply