O ma ṣe o, oṣere tiata Yoruba ku lojiji!

Kazeem Aderohunmu 

Pẹlu ibanujẹ lawọn oṣere tiata Yoruba fi kede iku ọkan pataki ninu wọn to ku lọjọ Ẹti, Furaidee.

Ọkanninu awọn oṣere naa, Kunle Afod, lo kọkọ gbe e sori ẹrọ agbọrọkaye, Instgiraamu, rẹ, nibi to kọ ̀ọ si Arabinrin Ẹniọla Kuburat naa ti dagbere faye pe o digbooṣe.

Ohun ti Kunle Afod, sọ ni pe aisan ranpẹ naa lo ṣe iya ọhun ti iku fi pa a.

Lara awọn ti wọn ti kẹdun iku obinrin yii lori instagiraamu Kunle ni Sikiratu Sindodo, Olaitan Sugar atawọn mi-in.

About Alaroye

Journalist, Press man and News Researcher of the federal Republic of Nigeria

Check Also

Nitori obinrin, Danladi gun ọrẹ rẹ pa l’Ode-Aye

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ẹni ọdun mejilelogun kan, Money Danladi, ni wọn ti fẹsun kan …

Leave a Reply

//dooloust.net/4/4998019
%d bloggers like this: