O ma ṣe o, Oloye Ayọ Fasanmi ti ku o

Florence Babaṣọla, Oṣogbo

Ọkan pataki ninu awọn aṣaaju Yoruba, to tunjẹ ọkan ninu awọn olori ẹgbẹ Afẹnifẹre, Oloye Ayọ Fasanmi, ti jade laye o.

Ni nnkan bii aago mẹwaa alẹ ana lo ku sinu ile rẹ to wa lagbegbe Oke-fia, niluu Oṣogbo lẹni ọdun mẹrinlelaaadọrun.

One thought on “O ma ṣe o, Oloye Ayọ Fasanmi ti ku o

Leave a Reply