O maa ṣe o! Olori oṣiṣẹ lọfiisi gomina Kwara ti ku o

Stephen Ajagbe, Ilorin

Iroyin kan to tẹ wa lọwọ sọ pe Alhaji Aminu Logun ti i ṣe olori awọn oṣiṣẹ lọfiisi gomina ipinlẹ Kwara ti jade laye.

Ileewosan kan niluu Ilọrin ni wọn lọkunrin naa ku si lonii, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee.

Ohun ta a gbọ ni pe o ṣee ṣe ko jẹ arun Korona lo pa a.

Leave a Reply