Ọjọ Ẹti, Furaidee, ni wọn sun igbẹjọ Sunday Igboho si

Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọla ni ile-ẹjọ giga to jokoo gbọ ẹjọ naa ni orileede Olominira Benin sun igbẹjọ Sunday Igboho si.

 

Leave a Reply