Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oni, ti waja

Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oluṣọla Oni, ti waja.

Akọwe iroyin fun Gomina Dapọ Abiọdun, Ọgbẹni Kunle Ṣomọrin, lo kede ipapoda ọba naa ninu atẹjade to fi sita lọjọ Ẹti, Furaidee ana.

 

Leave a Reply