Ọọni Ileefe rọ awọn ọdọ lati gba alaafia laaye

Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Ẹnitan Ogunwusi, ti rọ awọn ọdọ ki wọn gba alaafia laaye, ki kaluku si pada sile.
O ni, “Gẹgẹ bii ọdọ ti emi naa jẹ, mo fẹẹ fi da yin loju pe gbogbo aye pata lo ti gbọ ohun yin, fun idi eyi, ẹ gba alaafia laaye, ẹ jẹ ki ìjọba ṣatunṣe sí ohun gbogbo tẹ ẹ beere fun. Ẹ ma ṣe jẹ ki awọn janduku tọọgi gba a mọ ọn yin lọwọ, eyi tẹ ẹ ṣe yii naa lo n jẹ ohun. Ẹ ṣe sùúrù kí ohun gbogbo le dara.

One thought on “Ọọni Ileefe rọ awọn ọdọ lati gba alaafia laaye

Leave a Reply