Ọpẹ o, awọn ọlọpaa ti ri Sunday to n paayan l’Akinyẹle to sa lọ n’Ibadan mu

Ọlawale Ajao, Ibadan

Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọyọ, Olugbenga Fadeyi, ti fidi rẹ mulẹ pe ọwọ ti pada tẹ Sunday Shodipẹ, ọmọkunrin to maa n pa awọn eeyan l’Akinyẹle to sa lọ lagọọ ọlọpaa ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kọkanla, oṣu yii.

Ọga ọlọpaa naa ni ọrọ yii ko ni ariyajijyan ninu, ọwọ awọn ti tẹ ẹ. Ṣugbọn ko ti i ṣalaye bi wọn ṣe ri ọmọkunrin naa mu ati ọna ti wọn gba mu un.

Ẹ maa tẹti leko fun iroyin nipa eleyii.

Leave a Reply