O gbẹnu tan: Shaibu ki ọmọ to bi mọlẹ, o ba a sun karakara

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Kabak, nijọba ibilẹ Mubi-South, nipinlẹ Adamawa, ti mu  baale ile kan, Ọgbẹni Auwal Shaibu, ẹni ọdun mejilelogoji. Ẹsun ti wọn…

Eedi ree o! Mustapha gun ọrẹ ẹ lọbẹ pa l’Ọrẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu Majisireeti to wa lagbegbe Oke-Ẹda, niluu Akurẹ, ti ni ki ọkunrin ẹni…

Ijọba ipinlẹ Ondo fẹẹ gba ẹgbẹrun meji olukọ siṣẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ijọba ipinlẹ Ondo ti kede ipinnu rẹ lati gba ẹgbẹrun meji olukọ si…

Ibo gomina: Eyi lawọn to fẹẹ dupo l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Asiko ta a wa yii ki i ṣeyi to dẹrun rara fun gbogbo…

Eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ nibi isinku Olubadan ilẹ Ibadan

Faith Adebọla Ọpọ eeyan ni ipapoda ọba naa ba lojiji, tori wọn o reti ẹ, ti…

Alima yii ti ha o, awọn akẹkọọ ileewe alakọọbẹrẹ mẹta lo ji gbe l’Ekoo

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ijegun, nipinlẹ Eko, ni iyaale ile kan, Abilekọ Akintọla Alima, ẹni ogoji ọdun, ti wọn fẹsun ijinigbe kan wa bayii. Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹta,  ni ọwọ awọn agbofinro…

Lori iku Mohbad, awọn ọlọpaa ti ju Prime Boy satimọle o

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Panti, niluu Yaba, nipinlẹ Eko, ni Ọgbẹni Ibrahim Owodunni, ẹni tawọn eeyan…

Ikunlẹ Abiyamọ o, ina jo awọn ọmọde meji pa nipagọ ogunlende ti wọn wa

Adewale Adeoye Ni ipagọ ogun-le-n-de kan ti ijọba  ko awọn araalu tawọn agbebọn atawọn ọmọ ẹgbẹ Boko Haram ṣọṣẹ fun si…

Awọn agbebọn ya bo ileewosan ijọba, wọn ji igbakeji ọga agba ati baba ọlọde gbe lọ 

Adewale Adeoye Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kejila, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, ki i ṣe eyi to dara rara fawọn eeyan agbegbe Ituku-Ozalla, niluu Enugu, pẹlu…

Ọkọ ajagbe wo lu tasin l’Ondo, eeyan mẹta lo ku

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan mẹta lo ku, ti ẹni kan si fara pa ninu ijamba kan,…

Dauda fi miliọnu mẹẹẹdogun ninu owo ileeṣẹ to n ba ṣiṣẹ ta tẹtẹ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọga ileeṣẹ aladaani kan, Alaaja Risikat Shao, ti gbe ọkan ninu awọn oṣiṣẹ…