Wahala n bọ o! Wọn lawọn kan fẹẹ pa Arẹgbẹṣọla l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igun kan ninu ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), nipinlẹ Ọṣun, ti wọn…

O ma ṣe o, nibi ti Miracle ti n pọn omi ẹrọ lọwọ ni ina ẹlẹntiriki ti pa a

Adewale Adeoye Awọn ọlọpaa agbegbe Lafẹnwa, niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, ti lawọn maa too bẹrẹ iwadii nipa iṣẹlẹ kan to gbẹmi Oloogbe Miracle Ogbonna, to…

Bassirou, Aarẹ tọjọ ori rẹ kere ju lorileede Senegal ti gori aleefa

Faith Adebọla Ni bayii, Aarẹ tuntun lorileede Senegal, Ọgbẹni Bassirou Diomaye Faye, ẹni ọdun mẹrinlelogoji (44) pere,…

Ọlọdẹ yinbọn paayan, ibi to ti fẹẹ dọgbọn ju u nu lọwọ ti tẹ ẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Rogbodiyan nla bẹ silẹ niluu Iwo, nipinlẹ Ọṣun, laaarọ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ…

O ṣẹlẹ, Yọmi Fabiyi kọ lẹta siyawo Mohbad, eyi lohun to wa nibẹ

Monisọla Saka Oṣerekunrin ilẹ wa nni, Yọmi Fabiyi, ti kọwe si Ọmọwumi Alọba, ti i ṣe…

Ab’ẹẹri Sanusi, suuti lo fi tan ọmọkunrin to larun ọpọlọ to fi fipa ba a lo pọ

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Bauchi ti tẹ Sanusi Umar, ẹni ọdun mẹtalelogun (23), to…

Ẹfun abeedi! Lasiko ti ọlọpaa yii ati ọrẹbinrin rẹ n muti lọwọ lo gun un pa toyun-toyun

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa orilẹ-ede South Africa, ti tẹ ọkan lara wọn to gun ọrẹbinrin…

Ọwọ ti tẹ ẹ o: Lẹyin bii ọdun meji ti wọn ti n wa a, ọwọ ọlọpaa tẹ ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun kan, Bọde…

Ṣeun Kuti ju bọmbu ọrọ: Bo ba jẹ ọmọ olowo lẹ fun loyun, ṣe ẹ maa sọ pe ẹ fẹẹ ṣe ayẹwo ẹjẹ (DNA)

Monisọla Saka Olorin taka-sufee ilẹ wa to jẹ ọmọ bibi inu Fẹla Anikulapo Kuti, ti i…

Aye le o: Wọn di oku ọmọkunrin kan sinu apo, wọn si gbe e sidii ọgẹdẹ n’Iyin-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Kayeefi nla lo jẹ fun gbogbo eeyan ilu Iyin-Ekiti, nijọba ibilẹ Irepọdun/Ifẹlodun, nipinlẹ…

Ajalu buruku! Igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa Eko pokunso

  Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lọwọ lọrọ iku igbakeji Kọmiṣanna ọlọpaa nipinlẹ Eko, Oloogbe D.C.P Gbolahan Oyedemi, to…