Wọn ti mu obinrin ọmọ Naijiria kan to gbe egboogi oloro ni South-Africa

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe ‘Johannesburg Metropolitan Police Department’ (JMPD), to wa lorileede South Africa, ni iyaale ile ẹni ọdun mọkandinlogoji kan ti…

Ọjọ ọdun Itunu aawẹ mi Ibrahim lọọ ji mọtọ araalu kan gbe

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ  ti wọn fẹsun iwa ọdaran kan wa, o n ran wọn lọwọ ninu iwadi…

O n rugbo bọ o! Ọba ti ile-ẹjọ rọ loye tun fẹẹ fawọn eeyan joye niluu Ọ̀là

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati le dena wahala ati idaluru to ṣee ṣe ko waye lopin ọsẹ…

Baalẹ ọkọ ilu ti n kawọ pọnyin rojọ toun tilẹkẹ oye lọrun, eyi lẹsun buruku ti wọn fi kan an

Ọlawale Ajao, Ibadan Baalẹ ọkọ ilu ti n kawọ pọnyin rojọ toun tilẹkẹ oye rẹ, ẹsun…

Wahala n bọ lori oye Olubadan, wọn ni Ọlakulẹhin to kan ko ti i le jọba

Ọlawale Ajao, Ibadan Iyapa-ẹnu, eyi ti iru ẹ ko ṣẹlẹ ri, ti bẹrẹ si i waye…

O ma ṣe o, idile kan parun sinu ijamba ọkọ

Adewale Adeoye Beeyan ba jori ahun, to ba ri bi ijamba ọkọ  ṣe ṣeku pa idile kan, ninu…

O ṣẹlẹ! Wọn fẹẹ wọ alaga APC,  Ganduje, iyawo ati ọmọ rẹ lọ si kootu, eyi lohun ti wọn ṣe

Adewale Adeoye Gbogbo eto lo ti pari bayii lori bi awọn alaṣẹ ijọba ipinlẹ Kano ṣe maa foju Alhaji Umar Ganduje ti…

Wọn ti mu tọkọ-taya yii, ayederu ọti ni wọn n pọn faraalu mu

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa Zone 2, ni awọn tọkọ-taya meji kan ti wọn n pọn ọti waini atawọn…

O ma ṣe o, ọkọ akoyọyọ tẹ ọlọkada kan pa l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọmọkunrin kan lọkọ akoyọyọ tun tẹ pa lori ọkada niluu Ondo, lọjọ Iṣẹgun,…

Eyi lawọn ti ẹgbẹ APC fọwọ si pe wọn kunju oṣuwọn lati dupo gomina l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbimọ ti ẹgbẹ All Progressive Congress lorilẹ-ede yii gbe kalẹ lati ṣe ayẹwo…

Oluwoo we lawani fun Imaamu Agba tuntun niluu Iwo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti we lawani fun Muhammed…