Nibi ti ọmọkunrin yii ti n mura ati se ẹran ẹlẹran to ji gbe lawọn ọlọpaa ti mu un

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Kurikyo, nijọba ibilẹ Lafia, nipinlẹ Nasarawa, ni Ọgbẹni Mohammed Tanko, ẹni ti wọn fẹsun kan pe o lọọ ji ẹran agbo nla kan…

Wọn ti mu Balogun o, ayederu ṣọja to n faṣọ ijọba lu jibiti l’Ekoo

Adewale Adeoye Lagbegbe Isheri-Ọṣun, nipinlẹ Eko, lọwọ awọn ọlọpaa ti tẹ ayederu ṣọja kan to pe ara rẹ ni Sajẹnti Major Fẹmi Balogun, pẹlu aṣọ ijọba lọrun…

Wahab yii ma laya o, ọlọpaa lo fẹẹ ja lole ti wọn fi mu un

Adewale Adeoye Afurasi adigunjale kan, Akinjọbi Wahab, ẹni ọdun mọkandinlogun, ti ṣi iṣẹ ṣe bayii o. Ọlọpaa ti ko wọsọ…

Kindinrin eeyan mẹta, ọkan mẹta, eegun ẹyin ati ahọn ni wọn ba lọwọ Aafaa Idris l’Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Aafaa kan ti wọn porukọ rẹ ni Oluwafẹmi Idris, lọwọ ti tẹ l’Akoko,…

Eyi lohun to wa laarin emi ati Olubadan to waja- Ọbasanjọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Yatọ si pe “Ẹgbọn mi”, “Ẹgbọn mi” l’Olubadan to waja, Ọba Mohood Ọlalekan…

Nitori obinrin, ṣọja gun ọmọkunrin yii pa m’ọnu ṣọọbu rẹ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Ọkunrin oniṣowo kan, Ezeani Ebuka, ni ṣọja kan ti gun lọbẹ pa mọ’nu…

Ọpẹyẹmi tan ọrẹ ẹ lọ sinu igbo, lẹyin to pa a tan lo ji ọkada rẹ gbe lọ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti tẹ ọkunrin kan, Dọlapọ Babalọla, lori ẹsun ṣiṣeku…

Ezekiel, ọmọ ọdun mẹwaa, pa ọrẹ rẹ lasiko ti wọn n gba bọọlu l’Ekoo

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ejigbo, nipinlẹ Eko, ni ọmọ ọdun mẹwaa kan, Evbota Ezekiel, to pa ọrẹ rẹ, Oloogbe Israel Ogunlẹyẹ, ẹni ọdun mẹwaa, wa bayii,…

Ọwọ tẹ Mustapha to n ta ibọn fawọn ọdaran

Adewale Adeoye Ọkan pataki lara awọn to n ta ibọn fawọn ọdaran laarin ilu Mandela, nijọba ibilẹ Minna, nipinlẹ Niger, Ọgbẹni Mustapha Ishaku, lọwọ awọn ọlọpaa agbegbe naa…

Nitori bi ita ṣe ri, obinrin ara Amẹrika yii dana iṣinu aawẹ fawọn Musulumi n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Latari ọwọngogo ounjẹ to gbode, paapaa ju lọ lasiko aawẹ Ramadan yii, obinrin…

Awọn agbebọn ya bo ṣọọṣi Sẹlẹ ni Mowe, wọn ji eeyan meji gbe lọ

Faith Adebọla Atẹgun iṣẹlẹ ijinigbe to n fẹ yika orileede yii ti tun wọ ipinlẹ Ogun…