Monisọla Saka Ajọ to n ri si ọrọ kaadi idanimọ lorilẹ-ede yii, National Identity Management Commission…
Ọlọkada yii loun ko fẹẹ ri ọdun 2025, eyi lohun to ṣe funra ẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Nigba ti gbogbo aye n gbadura lati la ọdun 2024 to n pari…
Awọn eto ọrọ aje ta a n ṣe atunṣe rẹ ti bẹrẹ si i so eeso rere –Aarẹ Tinubu
Adewale adeoye ‘‘Bi ẹkun ba dalẹ ni, ayọ ati ireti ọtun n bọ lowurọ, diẹ lo…
Orileede Brazil ni ọmọ Naijiria yii ti n gbe kokeeni bọ ti wọn fi mu un n’Ikẹja
Adewale adeoye Ọdọ ajọ to n gbogun ti gbigbe ati lilo egboogi oloro lorileede yii, ‘National…
Ọwọ Amọtẹkun tẹ Adekunle o, ọgẹdẹ lọọ ji loko oloko
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti mu ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn kan, Adekunle Omideyi,…
L’Ọṣun, oṣiṣẹ aṣọbode, iyawo atawọn ọmọ ẹ mẹrin jona mọle
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oṣiṣẹ aṣọbode kan ni ẹka ileeṣẹ naa nipinlẹ Ọyọ ati Ọṣun, Tijani Kabiru,…
Ileefọpo ilẹ wa ti NNPCL ṣi laipẹ yii ti dawọ iṣẹ duro o, paroparo nibẹ da bayii
Ireti awọn ọmọ Naijiria pe didun lọsan yoo so lori ọrọ epo bẹntiroolu pẹlu bi ileesẹ…
Ẹgbẹ oṣelu NNPP ti ni ki Adeleke maa palẹ eru rẹ mọ nileejọba
Ẹgbẹ oṣelu New Nigeria Peoples Party (NNPP), nipinlẹ Ọṣun, ti sọ pe ki Gomina Ademọla Adeleke…
Eyi lohun ti Gomina Adeleke ṣe fawọn oṣiṣẹ ijọba l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede pe ọjọ kin-in-ni, oṣu Kejila yii, lati bẹrẹ…
Eyi lohun ti Gomina Adeleke ṣe fawọn oṣiṣẹ ijọba l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede pe ọjọ kin-in-ni, oṣu Kejila yii, lati bẹrẹ…
Abadofin ti Aarẹ Tinubu gbe siwaju awọn aṣofin di wahala nla
Adewale adeoye Fun bii wakati kan tabi ju bẹẹ lọ ni rogbodiyan nla ati idarudapọ fi…