Abẹẹ rawọn ọmọleewe yii, niṣe ni wọn jira wọn gbe, ti wọn si n beere owo itusilẹ lọwọ obi wọn

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn akẹkọọ meji kan, Ayọdele Balogun, ẹni…

L’Ondo, adajọ ni ki Wisdom sare lọọ lo ọdun mẹfa lẹwọn pẹlu iṣẹ aṣekara

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu Majisireeti to wa niluu Ondo, nijọba ibilẹ Iwọ-Oorun Ondo, ti ni ki…

Ọwọ tẹ awọn eleyii, oriṣiiriṣii ayederu ọti ni wọn n ṣe l’Agege

Adewale Adeoye Mẹrin lara awọn ọdaran kan to jẹ pe wọn ti jingiri ninu ṣiṣe ayederu ọti waini atawọn oriṣiiriṣii ọti…

Ere agbere: Iyaale ile binu para ẹ lẹyin t’ọkọ ka ale mọ ọn lori

Adewale Adeoye O da bii pe itiju aa ti i gbọ lo mu ki iyaale ile…

Abiru ki leleyii, awọn agbebọn kọ lu mọto akero, wọn ji ero inu ẹ gbe lọ

Adewale Adeoye Odidi mọto ero kan to jẹ ti ipinlẹ Katsina, iyẹn, ‘Katsina State Transport Authority’ (KTSTA) lawọn agbebọn kan…

Lẹyin ọsẹ kan ti Olubadan waja, Makinde ṣabẹwo sawọn ẹbi ọba naa

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ kan  ti Olubadan ilẹ Ibadan, Ọba Mohood Ọlalekan Balogun waja, Gomina…

Eyi ni b’ọwọ ṣe tẹ Fatai nibi ti oun atawọn ẹgbẹ ẹ ti fẹẹ fọ banki n’Irele 

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lasiko ti afurasi adigunjale kan, Fatai Bání atawọn ẹgbẹ rẹ fẹẹ fọ awọn…

Eeyan meji ku, ọpọ ṣeṣe, ninu ijanba ọkọ lọna Ogbomọṣọ si Isẹyin

Ọlawale Ajao, Ibadan Loju-ẹsẹ leeyan meji jẹ Ọlọrun nipe ninu ijanba ọkọ kan to waye loju…

O ṣẹlẹ, Portable hu oku iya ẹ, eyi lohun to fi i ṣe

Monisọla Saka Gbajumọ olorin taka-sufee ilẹ wa tawọn ọdọ fẹran nni, Habeeb Okikiọla Badmus ọmọ Ọlalọmi,…

Iyawo Tinubu gba awọn ọmọ Naijiria nimọran: Ẹ yaa pada sidii iṣẹ agbẹ

Faith Adebọla Lojuna ati wa ojutuu si ọwọngogo ọja ati ebi to gbode kan lorileede Naijiria…

Ẹyin tẹẹ fẹẹ mọ iku to pa Mohbad, esi ayẹwo ẹ ti delẹ o

Faith Adebọla O jọ pe suuru ati ireti ọlọjọ gbọọrọ tawọn ololufẹ gbajugbaja onkọrin hipọọpu to…