Eemọ! Ọbọ ni ọkunrin yii pa to fi n kawọ pọnyin rojọ

Monisọla Saka Ọrọ buruku toun tẹrin, ni iṣẹlẹ kan to waye niluu Awka, ti i ṣe…

Idajọ iku lo yẹ ki wọn maa fun awọn ajinigbe-Rẹmi Tinubu

Oluṣẹyẹ Iyiade Obinrin akọkọ l’orilẹ-ede Naijiria, Abilekọ Olurẹmi Tinubu, ni ẹjọ iku lo yẹ ki wọn…

Ọlọpaa gba ẹgunjẹ lọwọ adigunjale, ni wọn ba tu u silẹ

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Mature, tile-ẹjọ Magisireeti kan to wa lagbegbe Morningside, lorileede Zimbabwe, ni wọn foju ọlọpaa mẹta…

Eleyii ga o, wọn yinbọn pa ọlọpaa marun-un lẹnu iṣẹ 

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ebonyi, ṣi n wa awọn agbebọn kan ti wọn yinbọn pa ọlọpaa marun-un lẹnu…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, awọn akẹkọọ Fasiti KWASU mẹrin dawọ jọ lu ẹlẹgbẹ wọn pa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Laaarọ kutukutu ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹjọ, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, ni…

Wọn yan ọmọ Yoruba gẹgẹ bii akọwe agba nipinlẹ Anambra 

Monisọla Saka Anambra, Ọjọgbọn Charles Soludo, ti fi apẹẹrẹ rere lelẹ ninu eto iṣelu ilẹ Naijiria,…

Nitori bi Tinubu ṣe yan ọmọ Ganduje sipo, awọn ọmọ ẹgbẹ kan n binu

Adewale Adeoye Orin pe, ‘a ko le sin baba ka tun sin ọmọ’ lawọn ara Oke- Ọya kan n kọ setiigbọ Aarẹ Bọla…

Eyi ni bi awọn adigunjale ṣe pa ọlọpaa meji lasiko ti wọn fọ banki meji ni Kogi

Adewale Adeoye Ifa ko fọ rere fawọn agbofinro meji kan pẹlu bi awọn adigunjale ṣe pa…

Iṣẹlẹ ijinigbe Kaduna ati Borno, fi han pe Tinubu ko kunju oṣuwọn – Atiku Abubakar

Adewale Adeoye ‘Bi gbogbo nnkan ṣe ri yii, ti eku ko ke bii eku mọ, ti ẹyẹ ko ke bii ẹyẹ, t’ọmọ eeyan…

Eyi le o, janduku kan lọ ibọn mọ wọda lọwọ, lo ba yin in mọ fọganaisa n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ibẹrubojo gbilẹ lagbegbe Òke-Kúrá, niluu Ilọrin, lọjọ Ẹti, Furaidee ọjọ kẹjọ,…

Aye le o, ki lo waa le mu baba ẹni ọgọrin ọdun yii pokunso l’Ekoo

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii lọrọ baba agbalagba kan, Oloogbe Isiaka Ayinde, ẹni ọgọrin ọdun to pokunso sinu…