Ọwọ ba Yusuf at’ọrẹ ẹ, awọn akẹkọọ-binrin ni wọn maa n digun ja lole lositẹẹli KWASU 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun, owe yii lo ṣe rẹgi…

Awọn eeyan bara jẹ gidigidi nibi isinku Sisi Quadri, eyi lohun ti wọn sọ nipa rẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ka ku lọmọde ko yẹ ni, o san ju ka dagba ka ma…

O ma ṣe o, Sisi Quadri n mura ilu oyinbo lọwọ niku mu un lọ

    Ọrẹoluwa Adedeji Yoo ṣoro ki iku oṣere adẹrin-in-poṣonu nni, Tọlani Qadri Oyebamiji, ti gbogbo…

 Eyi laṣiiri iku to pa Sisi Quadri

Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe oṣerekunrin ti gbogbo eeyan fẹran daadaa nni, Tọlani Qadri Oyebamiji,…

Ajalu buruku lagbo tiata! Sisi Quadri ku lojiji

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan ninu awọn oṣere ilẹ wa tawọn eeyan fẹran daadaa…

Ẹ woju awọn ọdaran ti wọn pa Rianat lasiko to fẹẹ lọọ ra kulikuli l’Ọffa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Aṣe ootọ lowe Yoruba to ni iyan ogun ọdun a maa jo ni…

Gende meji dero kootu l’Akurẹ, foonu ni wọn ji nibi eto isinku Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti wọ awọn afurasi ole meji kan, Oluṣẹyẹ Adefila…

Atọlagbe yii buru o! Lẹyin to fipa ba obinrin kan sun tan lo ge ẹran ẹ wẹlẹwẹ, o ba dana sun un ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọtafa-soke yido-bori, b’ọba aye ko ri ọ, tọrun n wo ọ. Ọrọ ikilọ…

Bi gbogbo nnkan ṣe ri bayii lorileede Naijiria, ẹbi mi ni-Aarẹ Tinubu

Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti ni oun gba ẹbi bi gbogbo nnkan  ti ṣe ri…

Wọn ti mu Bethel, ayederu agunbanirọ to rapala wọ ipagọ wọn

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Nasarawa, ti mu ayederu agunbanirọ kan, Ọgbẹni Ogeh Bethel Chibuife, to si n…

Eeyan mẹta gbẹmi-in mi ninu ijamba ọkọ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ariwo, ‘ikunlẹ abiyamọ’ lawọn eeyan ti wọn gba oju ọna Oṣogbo si Ikirun,…