Ko gba ko dija: Ibrahim fọbẹ gun akẹkọọ ẹgbẹ ẹ to fẹẹ maa yan lọrẹẹ nitori tiyẹn ko gba fun un

Adewale Adeoye Ko gba ko dija ni wọn maa n sọ, ṣugbọn ọrọ ko ri bẹẹ…

O ti waa doju ẹ! Awọn agbebọn ya bo awọn ara ọja, wọn pa eeyan bii ogun

Adewale Adeoye Olori ilu kan, atawọn araalu bii ogun, lawọn agbebọn to ya wọ’nu ọja iṣẹnbaye kan to wa…

Oloro tilu Oro, AbdulRafiu Ọlaniyi Ajiboye Oyelaran, ti waja

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrazaq, ti ba awọn eeyan ilu Oro, nijọba Ìfẹ́lódùn,…

Eyi lohun ti Gumi sọ lori ọkunrin ti wọn mu pe o n ṣatilẹyin fawọn afẹmiṣofo

Monisọla Saka Aafaa nla to filu Kaduna ṣebugbe, to si gbajumọ lori ọrọ awọn ajinigbe ati…

Awọn eleyii naa jira wọn gbe, inu igbo kan ni wọn lọọ sa si

Monisọla Saka Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, Adegoke Fayọade, ti gboṣuba kare fawọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ti wọn…

Awọn ẹlẹsin ibilẹ, aafaa nla atawọn agba wolii pade nibi eto adura ọjọ kẹjọ Olubadan to waja

 Ọlawale Ajao, Ibadan Bo ba ṣe pe bi ẹsin eeyan ṣe pọ niye to l’Ọlọrun yoo…

Gbogbo ileewe pamari ati sẹkọndiri gbọdọ ni fẹnsi ati kamẹra aṣofofo nipinlẹ Ogun -Kọmiṣanna ọlọpaa

Faith Adebọla Ọkan-o-jọkan amọran ati aba ti waye lati ro eto aabo lagbara dan-in-dan-in lawọn ileewe…

Nibi tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti n ṣepade l’Oṣogbo lawọn ọlọpaa ti ko wọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹta ni ọwọ ọlọpaa ti tẹ lagbegbe Oṣogbo bayii.…

Ọwọ ti tẹ Sodiq l’Oṣogbo, ọkada mẹta ni wọn ka mọ ọn lọwọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan bayii ni tolohun, eyi lo ṣẹ mọ…

Abẹẹ rawọn ọmọleewe yii, niṣe ni wọn jira wọn gbe, ti wọn si n beere owo itusilẹ lọwọ obi wọn

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn akẹkọọ meji kan, Ayọdele Balogun, ẹni…

L’Ondo, adajọ ni ki Wisdom sare lọọ lo ọdun mẹfa lẹwọn pẹlu iṣẹ aṣekara

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu Majisireeti to wa niluu Ondo, nijọba ibilẹ Iwọ-Oorun Ondo, ti ni ki…