Awọn Afẹnifẹre ti sọrọ: Adebanjọ ṣi ni olori ẹgbẹ wa

Faith Adebọla Afaimọ ni owe awọn agba kan to sọ pe ai fagba fẹnikan ni ko…

Nitori biliọnu rẹpẹtẹ ti wọn fẹẹ fi tun Kwara Hotel ṣe, Mustapha sọko ọrọ si Gomina AbdulRasaq 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Eekan kan ninu ẹgbẹ oṣelu Onitẹsiwaju, All Progressives Congress (APC), nipinlẹ Kwara, Mashood…

Ẹ woju ajinigbe to pa Nabeeha, ọkan ninu awọn ọmọbinrin mẹfa ti wọn ji

Faith Adebọla Ṣe ẹ ranti iṣẹlẹ ijinigbe kan to waye niluu Abuja, olu-ilu ilẹ wa lọjọ…

 Ẹ wo Ibrahim: Igbakeji ọga awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, ibọn rẹpẹtẹ ni wọn ba lọwọ ẹ

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti fọwọ ofin mu Ọgbẹni Ibrahim AbdulAzeez, ti wọn sọ pe ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun ni, ati pe ọpọ igba…

O ma waa ga o, agbebọn mura bii ẹlẹhaa, lo ba pa ọga ọlọpaa meji danu

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ ọhun di ẹni ori yọ, ipade dile, lasiko ti agbebọn kan to mura bii ẹlẹhaa lọọ kọju…

Orileede Mali, Niger ati Burkina-Faso ti kuro ninu ajọ ECOWAS

Adewale Adeoye Ni bayii, awọn ijọba ologun ti orileede Mali, Niger ati Burkina-Faso, ti kede pe awọn…

O ma ṣe o, iyawo atawọn ọrẹ ẹ marun-un pẹlu aburo ọkọ ku sinu ijamba mọto lọjọ kan naa

Adewale Adeoye Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu Kin-in-ni, ọdun 2024 yii ni iṣẹlẹ agbọ-kawọ-mọri kan ṣẹlẹ sawọn  idile kan to ṣẹṣẹ ṣegbeyawo alarinrin fawọn ọmọ wọn, ti iyawo…

Iru ifẹ wo ree: Nitori ti ọkunrin ja a kulẹ, akẹkọọ-binrin yii binu gbẹmi ara ẹ

Monisọla Saka Akẹkọọ-binrin onipele keji nileewe gbogboniṣe ijọba apapọ to wa niluu Mubi, nipinlẹ Adamawa (Federal…

Ọpẹ o, wọn ti ri akẹkọọ Fasiti Ilọrin ti wọn ji gbe pada, eyi ni bi wọn ṣe ri i

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akẹkọọ Fasiti ilu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, Moyọṣọrẹ Bright, to wa ni ipele kin-in-ni…

L’Ọṣun, wọn yinbọn pa aṣaaju ẹgbẹ oṣelu PDP to wale lati orileede Amẹrika

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin ọmọ ẹgbẹ PDP kan to jẹ olukọ lorileede Amẹrika, Ọgbẹni Richard Idowu,…

Adajọ ko gba ẹbẹ Udom to gun ọrẹ rẹ pa, wọn ju u sẹwọn Kirikiri

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Oyindamọla Ọgala, tile-ẹjọ giga kan to wa niluu Ikeja, nipinlẹ Eko, ni wọn wọ Ọgbẹni Emmanuel Udom, to gun ọrẹ rẹ pa ba. Ẹsun…