Wọn ti mu Abba Kyari, ọga ọlọpaa ti wọn lo n ṣowo ẹgboogi oloro

Faith Adebọla Ọwọ agbofinro ti ba DCP Abba Kyari, ọga ọtẹlẹmuyẹ ana ti wọn fẹsun kan…

Makinde fọwọ si Lekan Balogun gẹgẹ bii Olubadan tuntun

Jọkẹ Amọri Ọsan ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, fọwọ…

NDLEA lawọn n wa Abba Kyari, wọn lọga ọtẹlẹmuyẹ naa n ṣowo egboogi oloro

Faith Adebọla Adepele lawọn ẹsun ti wọn ka si ẹsẹ DCP Abba Kyari, da bayii o,…

Ẹgbẹ olukọ ileewe giga fasiti fẹẹ bẹrẹ iyanṣẹlodi oṣu kan lati fa ijọba leti

Jọkẹ Amọri Gbedeke oṣu kan pere ni awọn igbimọ ẹgbẹ awọn olukọ nileewe giga fasiti ilẹ…

Irọ ni, Tinubu ko tọ sara nigba to lọọ ki Awujalẹ, awọn ọta lo n sọ bẹẹ kiri-Ajiboye

Adewumi Adegoke Ọga agba eto iroyin ati ipolongo fun (SGMC) ẹgbẹ to n ṣatilẹyin fun Aṣiwaju…

Nitori bi wọn ṣe ti i mọle lọna aitọ, Sunday Igboho pe ijọba ilẹ Bẹnnẹ lẹjọ, o ni afi ki wọn san Miliọnu kan Dọla foun

Nitori bi wọn ṣe ti i mọle lọna aitọ, ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ ti…

Awọn ọdọ dana sun eeyan meji ti wọn ba ori eeyan lọwọ wọn l’Ọja-Ọdan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Idajọ oju-ẹsẹ lawọn ọdọ kan ti wọn le lọgọrun-un ṣe fawọn ọkunrin meji…

Makinde ṣabẹwo si Olunlọyọ, o fun un ni mọto olowo nla

Olawale Ajao, Ibadan Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeyan ṣi n ki…

Awọn janduku kọ lu ile Sunday Igboho n’Ibadan

Adewumi Adegoke Ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii ni ariwo gba ilu kan pe awọn janduku kan…

Ile alaja mẹta ti wọn n kọ lọwọ da wo l’Ekoo

Jọkẹ Amọri Ile alaja mẹta kan ti wọn n kọ lọwọ to wa ni Akanbi Crescent,…

Makinde yoo kede Olubadan tuntun lọjọ Aje, Mọnde 

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹrinla, oṣu keji, ọdun 2022 yii, nijọba ipinlẹ Ọyọ yoo kede ẹni ti…