Ẹ ma reti pe ayipada kankan labẹ ijọba Buhari ati APC, o maa buru si i ni-Alaga PDP

Faith Adebọla Alaga apapọ fẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party (PDP), Sẹnetọ Iyorchia Ayu, ti ṣekilọ fawọn…

Lọọya Sunday Igboho to gba awọn ọmọ ẹ silẹ lahaamọ DSS loun ko ṣe agbẹjọro ẹ mọ

Faith Adebọla  Ọkan pataki ninu awọn agbẹjoro to n ṣoju fun gbajugbaja ajijagbara ilẹ Yoruba nni,…

Makinde ṣedaro Olubadan ilẹ Ibadan to waja

Ọlawale Ajao, Ibadan Bo tilẹ jẹ pe baba naa ti dagba, gbogbo eeyan ni ipapoda Olubadan…

Eto ti n lọ lati sinku Ọba Saliu Adetunji, Olubadan ilẹ Ibadan, to waja

Jọkẹ Amọri Bi gbogbo nnkan ba lọ bi wọn ṣe ṣeto rẹ, ọsan ọjọ Aiku, Sannde,…

Eyi ni asọtẹlẹ Baba Adeboye ati Dokita Olukọya fọdun 2022

Adefunkẹ Adebiyi  Awọn pasitọ agba meji ni Naijiria, Olori ijọ Irapada, Baba Enoch Adeboye ati Dokita…

Mo ti pin ogun mi lọdun to kọja, nigba ti dokita ni aisan to n ṣe mi ko gboogun- Kẹmi Afọlabi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nnkan n ṣẹlẹ niju, wọn o gbọ letile, iyẹn lọrọ oṣere tiata to…

Gende meji ku sodo lọjọ aisun ọdun tuntun n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu kejila, ọdun to kọja yii, iyẹn lọjọ…

Irọ ni o, emi o sọ pe mo fẹẹ dupo gomina lọdun 2023 o- Olori aṣofin Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni Abẹnugan ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Kwara, Họnarebu Yakubu Danladi-Salihu,…

Ọmọwumi ti dero agọ ọlọpaa o, ija ẹnikan lo n gbe to fi gun Ahmed nigo pa l’Ọta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹka ti wọn ti n fọrọ wa awọn apaayan lẹnu wo ni Ọmọwumi…

O ma ṣe o, moto ọlọpaa tẹ ọga ọlọpaa pa l’Ado-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Inu ọfọ nla ni ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti wa bayii latari bi ọkọ…

Lẹyin to san miliọnu mẹrin, awọn ajinigbe tu oloye Ijan-Ekiti silẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin to ti lo ọjọ meje nigbekun wọn, awọn ajinigbe ti tu Oloye…