‘Ọdọ iya iyawo mi ni mo maa n tọju ibọn ta a fi n ṣiṣẹ ijinigbe ati ole jija si’

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Johnson Apotire, Jimọh Dele, ti wọn tun maa n pe ni Dele Petim,…

Ẹ wo Fatima, obinrin to n gbe nnkan ija oloro fawọn agbebọn ninu igbo

Faith Adebọla  Beeyan ba kọkọ wo bi obinrin ẹni ọgbọn ọdun yii ṣe da hijaabu bori…

Loootọ ni Tinubu bẹbẹ fun atilẹyin mi lati di aarẹ lọdun 2023 ni- Yakassai

Agba oloṣelu apa Oke-Ọya ilẹ wa kan, to tun jẹ agba ẹgbẹ Arewa Consultative Forum, Alaaji…

Akẹkọọ to ba tapa sofin yoo balẹ sile awọn ọmọ alaigbọran- Arigbabu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kọmiṣanna eto ẹkọ, Sayẹnsi ati Imọ ẹrọ nipinlẹ Ogun, Ọjọgbọn Abayọmi Arigbabu, ti…

Ile-ẹjọ kede awọn agbebọn to n paayan kiri bii afẹmiṣofo 

Faith Adebọla  Ile-ẹjọ giga apapọ kan niluu Abuja ti kede lọjọ Ẹti, Furaidee yii, pe ko…

Awọn oṣere fi atilẹyin han fun Tinubu lati di aarẹ ni 2023

Adefunkẹ Adebiyi Ọkunrin ọmọ Ibo kan to maa n ṣe tiata lede oyinbo ati ede Ibo,…

Ileeṣẹ ọlọpaa ilẹ wa gbe iwadii iku Timothy kuro l’Ọṣun lọ si Abuja

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Iroyin to n tẹ ALAROYE lọwọ bayii ti fidii rẹ mulẹ pe olu…

Awọn agbebọn tun gboro ni Jos, wọn paayan mẹwaa, wọn dana sun’le rẹpẹtẹ

Faith Adebọla  Bi oku ṣe sun rẹpẹtẹ ni abule Te’egbe, nijọba ibilẹ Bassa, nipinlẹ Plateau, bẹẹ…

Eto aabo ṣi maa buru ju bayii lọ, ayafi… – Ọbasanjọ

Faith Adebọla Aarẹ ilẹ wa tẹlẹ, Oloye Oluṣẹgun Arẹmu Ọbasanjọ, ti sọ pe eto aabo to…

O ma ṣe o! Ladọja dagbere faye n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Gomina ipinlẹ Ọyọ nigba kan ri, Sẹnetọ Rashidi Adewolu Ladọja, ti padanu aburo…

Ileṣa lawọn Fulani to ji ọmọ gbe n’Igbara-Odo lọọ gbe e pamọ si

Taofeek Surdiq,  Ado-Ekiti Awọn ọrẹ mẹta kan ti wọn jẹ Fulani, Mubarak Bello, Alli Ibrahim ati…