Lẹyin to san miliọnu mẹrin, awọn ajinigbe tu oloye Ijan-Ekiti silẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin to ti lo ọjọ meje nigbekun wọn, awọn ajinigbe ti tu Oloye…

Wọn lere asapajude ati aibikita awakọ lo fa bọọsi akero to ja bọ latori biriiji l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ajọ LASEMA to n ri si iṣẹlẹ pajawiri l’Ekoo, (Lagos State Emergency Management…

 Eeyan mẹtalelogun ku lori ọrọ ilẹ n’Igbọkọda

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan bii mẹtalelogun ni wọn ti pade iku ojiji latari ija ilẹ to…

Adajọ ni ki wọn yẹgi fawọn adigunjale mẹrin l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi,  Abẹokuta Lọjọ Ẹti, Furaidee, to kọja yii, ni awọn ọkunrin mẹrin kan ti wọn…

 Afaa Ọlayiwọla ti wọn ka ori eeyan mọ lọwọ l’Ondo ti ku sagọọ ọlọpaa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Afaa Tunde Ọlayiwọla tọwọ tẹ pẹlu ori eeyan tutu lọjọ Isẹgun, Tusidee, ọsẹ…

Adajọ ni ki wọn yẹgi fun adigunjale mẹrin l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Ẹti, Furaidee, to kọja yii, ni awọn ọkunrin mẹrin kan ti wọn…

Awọn agbebọn yinbọn pa Fada Adeleke l’Ogunmakin

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn agbebọn ti ẹnikẹni ko ti i mọ ibi ti wọn ti wa…

Wọn lẹnjinni lo fa ijamba ọkọ oju omi to fẹmi eeyan mẹta ṣofo ni Badagry

Faith Adebọla, Eko Eeyan mẹta lo dagbere faye nigba ti ọkọ oju omi akero kan doju…

Eyi nidi ta a fi tun ko awọn onibaara kuro loju titi n’Ibadan-Ọlayiwọla

Ọlawale Ajao, Ibadan Ijọba ipinlẹ Ọyọ, labẹ iṣakoso Gomina Ṣeyi Makinde, ti tun palẹ awọn to…

 Ọlọdẹ yinbọn paayan l’Ọrẹ, o ni ẹranko loun ri

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ariwo, ‘ẹ dakun ẹ saanu mi, iran mi o paayan ri, ọrọ yii…

Mo fọwọ si Ọṣinbajo lati dupo aarẹ, eeyan daadaa ni, o si ni ero rere-Babangida

Faith Adebọla Olori orileede wa laye ologun, Ajagun-fẹyinti Ibrahim Badamọsi Babangida ti fi atilẹyin rẹ han…