Ohunkohun ko le da ipade apapọ ẹgbẹ PDP duro lọjọ Satide yii-Okowa

Faith Adebọla  Pẹlu bawọn kan ṣe ko ọkan soke lori idajọ ile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun ti wọn lo…

Mutairu ati Wasiu si tan ọmọbinrin kan lati Eko lọ s’Ibadan, lẹyin ti wọn pa a tan ni wọn ge ori ẹ

Jọkẹ Amọri Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii lawọn ọlọpaa ṣafihan awọn afiniṣowo meji kan, Ismaila Wasiu, ẹni…

Daniel fẹẹ para ẹ n’Iyana-Ipaja, awọn LASEMA ni wọn doola ẹmi ẹ

Faith Adebọla, Eko. Ọpẹlọpẹ awọn ẹṣọ alaabo ajọ to n ri si iṣẹlẹ pajawiri nipinlẹ Eko…

Ibi tawọn ajagungbalẹ mẹta yii ti n yinbọn mọ araalu n’Igbẹsa lọlọpaa ti ko wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Loootọ ni wọn n’iku ogun ni i pa akinkanju, ṣugbọn Afaimọ ni ijagungbalẹ…

O ma ṣe o! Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ kan to waye lopopona…

Nitori oju ọna to bajẹ kọja sisọ, ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ fẹhonu han, wọn di marosẹ Eko si Abẹokuta pa

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ, ẹka tipinlẹ Eko ati Ogun, ti ṣediwọ fun lilọ bibọ…

Ẹgbẹ Afẹnifẹre taku: Afi ka jokoo lati jiroro lori ibagbepọ wa bii orileede

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ to n ja fun iṣọkan ọmọ Yoruba, Afẹnifẹre, ti sọ pe inu…

Buhari tun fẹẹ ya igba miliọnu dọla, wọn lawọn fẹẹ fi ra àwọ̀n ap’ẹ̀fọn

Faith Adebọla Lọtẹ yii, awọn aṣofin apapọ ti koro oju si ibeere ijọba apapọ pe ki…

Eyi ni idi ti Fayẹmi ko fi si nibi abẹwo tawọn gomina ilẹ Yoruba ṣe si Tinubu-Akeredolu

Jọkẹ Amọri Lati bomi pana ahesọ ti awọn kan n gbe kiri pe ija buruku n…

Nitori Sunday Igboho, Gumi sọko ọrọ sawọn aṣaaju ẹsin ilẹ Yoruba

Faith Adebọla Ilumọ-ọn-ka aṣaaju ati olukọ ẹsin Islam l’Oke-Ọya nni, Sheik Ahmed Abubakar Gumi, ti takoto…

Awọn oṣiṣẹ-fẹyinti ṣewọde l’Oṣogbo, wọn ni ki Gomina Oyetọla san owo awọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati agbegbe Old Garage, lawọn oṣiṣẹ-fẹyinti nipinlẹ Ọṣun ti gbera laaarọ ọjọ Iṣẹgun,…