Adajọ paṣẹ kijọba Eko da iweerinna olukọ fasiti OOU ti wọn gbẹsẹ le pada fun un

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi wọn ṣe gba iwe irinna olukọ fasiti kan, Ọmọwe Adeṣọla Adeleke,…

Lọjọ kan ṣoṣo, eeyan mẹjọ ku ninu ijamba ọkọ ni marosẹ Eko s’Ibadan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn marun-un lo ku lọwọ aarọ, l’Ọjọruu ti i ṣe ọjọ kẹtadinlogun, oṣu…

PDP yan igbimọ alaamojuto tuntun fun ipinlẹ Eko

Faith Adebọla, Eko Latari bi eto idibo abẹle to yẹ ko waye loṣu kẹwaa ninu ẹgbẹ…

Ọkọ Sẹkinat tawọn kan dumbu ni Ṣagamu n beere fun idajọ ododo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọgbẹni Isa Adesanya ti i ṣe ọkọ Sẹkinat Adeasanya tawọn kan dumbu lọjọ…

Wasiu Ayinde ti tun ni aya tuntun lọọdẹ, Emmanuella niyawo ọṣingin

Faith Adebọla Ko sirọ ninu ọrọ ti Yoruba maa n sọ pe ‘iyawo dun lọṣingin,’ tabi…

Isẹyin lọwọ ti tẹ Abubakar, ọkan lara awọn to sa l’ọgba ẹwọn Abolongo, l’Ọyọọ

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ọwọ awọn agbofinro ti tẹ ọkan lara awọn meji ti wọn sa lọgba ẹwọn lasiko tawọn…

Ile ori oke kan tun da wo lu awọn to n ṣiṣẹ lọwọ ni Badagry

Jọkẹ Amọri Iroyin to n tẹ ALAROYE lọwọ ni pe ile ori oke kan ti tun…

Nitori bi Iyalọja Folaṣade Tinubu-Ojo ṣe ti ọja wọn pa fun odidi ọjọ mẹrinla, awọn ọlọja Oyingbo fẹhonu han

Jọkẹ Amọri Tọkunrin-tobinrin, tọmọde-tagba, ni wọn tu jade laaarọ kutu Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, lati fẹhonu…

Lori iku akẹkọọ Fasiti Ifẹ, awọn ọlọpaa mu Dokita Adedoyin to ni Otẹẹli Hilton

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alukooro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọṣun, SP Yẹmisi Ọpalọla, ti sọ pe awọn ti…

Ọlọpaa sa kuro ni teṣan l’Akurẹ, nitori awọn ọlọkada to fẹẹ gbẹsan iku ẹlẹgbẹ wọn ti wọn pa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn ọlọpaa A Difisan to wa lagbegbe Oke-Ẹda, l’Akurẹ, ni wọn n…

 Abubakar wọ banki bii ẹni to fẹẹ fowo pamọ, lo ba ji ọkada nibẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Abubakar Salleh ree, ẹni ọdun mọkanlelọgbọn ni. Niṣe lo wọ banki kan ni…