Isẹyin lọwọ ti tẹ Abubakar, ọkan lara awọn to sa l’ọgba ẹwọn Abolongo, l’Ọyọọ

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ọwọ awọn agbofinro ti tẹ ọkan lara awọn meji ti wọn sa lọgba ẹwọn lasiko tawọn…

Ile ori oke kan tun da wo lu awọn to n ṣiṣẹ lọwọ ni Badagry

Jọkẹ Amọri Iroyin to n tẹ ALAROYE lọwọ ni pe ile ori oke kan ti tun…

Nitori bi Iyalọja Folaṣade Tinubu-Ojo ṣe ti ọja wọn pa fun odidi ọjọ mẹrinla, awọn ọlọja Oyingbo fẹhonu han

Jọkẹ Amọri Tọkunrin-tobinrin, tọmọde-tagba, ni wọn tu jade laaarọ kutu Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, lati fẹhonu…

Lori iku akẹkọọ Fasiti Ifẹ, awọn ọlọpaa mu Dokita Adedoyin to ni Otẹẹli Hilton

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alukooro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọṣun, SP Yẹmisi Ọpalọla, ti sọ pe awọn ti…

Ọlọpaa sa kuro ni teṣan l’Akurẹ, nitori awọn ọlọkada to fẹẹ gbẹsan iku ẹlẹgbẹ wọn ti wọn pa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn ọlọpaa A Difisan to wa lagbegbe Oke-Ẹda, l’Akurẹ, ni wọn n…

 Abubakar wọ banki bii ẹni to fẹẹ fowo pamọ, lo ba ji ọkada nibẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Abubakar Salleh ree, ẹni ọdun mọkanlelọgbọn ni. Niṣe lo wọ banki kan ni…

Amọtẹkun ipinlẹ Ogun ti mu Taiwo to ṣa Rasaki pa nitori kòkó n’Ijẹbu-Igbo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Ọwọ ikọ Amọtẹkun ipinlẹ Ogun ti tẹ ọmọkunrin kan, Taiwo Fatai; ẹni ọdun…

Wọle ati Saheed ko sakolo ọlọpaa, ole ni wọn n ja loju popo l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Awọn gende meji yii, Saheed Ojo, ẹni ọdun mọkanlelogun, ati Oluwọle Khalid, ẹni…

Ina tun jo eeyan marun pa ninu ijamba ọkọ ni marosẹ Eko s’Ibadan 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Tanka to gbe epo bẹntiroolu lo gbina lojiji, ni nnkan bíi aago marun-un…

To ba n lọ bo ṣe n lọ yii, awọn agbebọn maa fẹyin Naijiria balẹ laipẹ – Gomina Ortom

Faith Adebọla “Ọmọ Naijiria gidi ni mi, emi o dẹ ni i dakẹ nibi to ba…

Wọn ma ni wọn ko ri ọmọkunrin adẹrin-in poṣonu nni, Cute Abiọla

Jokẹ Amọri Titi di ba a ṣe n sọ yii ni wọn ṣi n wa ọkunrin…