Kiko ẹgbẹ afẹmiṣofo jọ, fifẹ lati doju ijọba de ati pipa araalu lawọn ẹsun tuntun ti wọn ka si Kanu lẹsẹ

Faith Adebọla Ọjọ kọkandinlogun ati ogunjọ, oṣu ki-in-ni, ọdun 2022, ni igbẹjọ yoo maa tẹsiwaju lori…

Ẹwọn n run nimu Saheed o, agbẹjọro lo lu ni jibiti l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọkunrin kan, Fakẹyẹ Saheed, ti foju bale-ẹjọ Majisreeti ilu Oṣogbo l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ…

Buhari ki Soludo, gomina Anambra tuntun ku oriire, o loun maa ṣiṣẹ pẹlu rẹ

Faith Adebọla Olori orileede wa, Aarẹ Muhammadu Buhari, ko fakoko sofo rara lati ki Ọjọgbọn Charles…

Awọn adari ẹgbẹ APC l’Abuja gbe isakoso ẹgbẹ le Akala lọwọ nipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi nnkan ko ṣe ṣenuure fun alaga tẹlẹ fẹgbẹ oṣelu All Progessives Congress, APC, nipinlẹ…

Ọlọpaa kan ọlọkada lẹsẹ, lawọn araalu ba lu u lalubami l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alubami lawọn eeyan agbegbe Owo-Ẹba, loju-ọna Garaaji Ileṣa, lu ọlọpaa kan l’Ọjọruu, Wẹsidee,…

Eyi ni bawọn agbebọn ṣe fẹmi eeyan mọkanla ṣofo laarin ọjọ meji

Faith Adebọla Igbe ẹkun ati aro lo gbode kan nipinlẹ Zamfara lasiko yii, paapaa nijọba ibilẹ…

Awọn akẹkọọ funjọba Kaduna ni ọjọ meje lati ṣawari awọn oṣiṣẹ ijọba ibilẹ mejidinlogun ti wọn ji gbe

Faith Adebọla  Agbarijọ awọn ẹgbẹ Oke-Ọya, ẹka ti awọn akẹkọọ Kaduna (Coalition of Northern Groups, Kaduna…

Nitori bi wọn ṣe n yọ owo awọn onibaara niyọkuyọ, awọn eeyan ya bo ileefowopamọ UBA n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Mọnde, ọṣẹ yii, lawọn onibaara ileefowopamọ UBA, ya bo Opopona Ibrahim…

Nitori gomina, awọn agba ẹgbẹ APC sọko ọrọ si Lai Muhammed ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Mọnde, ọṣẹ yii, lawọn agba ati adari ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ…

Wọn ti ko awọn Fulani tọwọ tẹ pẹlu nnkan ija oloro l’Akurẹ lọ sile-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileesẹ eto idajọ ipinlẹ Ondo ti wọ awọn Fulani mejidinlogun tọwọ tẹ lọsẹ…

Awọn aṣofin Eko ni kijọba sanwo fawọn teeyan wọn ku ninu ajalu ile to wo n’Ikoyi

Faith Adebọla, Eko Ileegbimọ aṣofin Eko ti sọ pe ki Gomina Babajide Sanwo-Olu tipinlẹ Eko ṣeto…