Azeez niyawo oun n yan ale, lo ba lu u pa toyun-toyun ni Ṣaki

Faith Adebọla Ẹlẹkọ ọrun ti polowo iku ojiji fun obinrin alaboyun kan, Abilekọ Nimọta Giwa, niluu…

Lẹyin to ge ori ọmọ rẹ ati tẹnikan lati fi ṣoogun owo, Monday tun lọọ ge ori obinrin to ku lasiko ibimọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Monday Karezu lọkunrin to gbe ori eeyan dani yii n jẹ, ẹni ọdun…

Akẹkọọ ki olukọ rẹ mọlẹ ni Fasiti Ilọrin, o lu u bii aṣọ ofi

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ to kọja yii, ni akẹkọọ Fasiti Ilọrin, nipinlẹ Kwara, Captain…

Akẹkọọ ki olukọ rẹ mọlẹ ni Fasiti Ilọrin, o lu u bii aṣọ ofi

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ to kọja yii, ni akẹkọọ Fasiti Ilọrin, nipinlẹ Kwara, Captain…

Awọn oṣiṣẹ ijọba meji tọwọ tẹ lori ẹsun tita ọmọ were lọna aitọ ti foju bale-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Meji lara awọn oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Ondo ti wọn fẹsun kan laipẹ yii…

Ẹlẹrii tijọba fẹẹ mu wa lẹru n ba oun lati koju Baba Ijẹṣa nile-ẹjọ

Faith Adebọla, Eko  Meji ninu awọn ẹlẹrii tijọba ipinlẹ Eko fọkan tẹ lati jẹrii ta ko…

Eyi ni beeyan mẹfa ṣe jona ku ninu ijamba ọkọ l’Ode-Aye

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan mẹfa ni wọn jona ku, tawọn ero mi-in si tun fara pa…

 Lẹyin wakati diẹ tawọn oniṣowo igi gẹdu fẹhonu han l’Akurẹ, Akeredolu pasẹ ṣiṣi igbo ọba

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lẹyin bii wakati diẹ tawọn oniṣowo igi gẹdu fẹhonu han l’Akurẹ, Gomina ipinlẹ…

Eeyan mẹta ku, ọpọ fara pa, ninu ijamba ọkọ Jẹbba si Bode-Saadu, ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Eeyan mẹta la gbọ pe o ku, nigba tawọn mi-in fara pa ninu…

 Ẹẹmeji ni mo daku nigba ti mo kọkọ laju ri oku iyawo mi ni mọsuari-Ọlakunrin

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pupọ ninu awọn ero to wa nile-ẹjọ giga, nibi ti igbejọ awọn afufasi…

A o ni i ṣatilẹyin foloṣelu kankan,  ayafi ti atunto Naijiria ba waye – Afẹnifẹre

Faith Adebọla, Eko “Mi o ni i fakoko ṣofo mọ lori ọrọ bi Buhari ṣe n…