Awọn obinrin fẹhonu han lọ saafin ọba, ni wọn ba dana sun ile kabiesi

Ọlawale Ajao Inu holahilo lawọn olugbe ilu ti wọn n pe ni Boko, nipinlẹ Plateau, wa…

Awọn agbebọn to ji baba atawọn ọmọ ẹ mẹfa gbe n beere fun ọgọta miliọnu Naira 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu wahala ati aibalẹ ọkan ni mọlẹbi kan lagboole Sokoto, Òkèkere, niluu Ilọrin,…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, ayalegbe lu lanlọọdu rẹ daku

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abubakar Sadiq, tile-ẹjọ kan to wa lagbegbe Kabusa, ‘Grade 1 Area Court, to wa niluu Abuja, ti i ṣe…

O ṣẹlẹ, David ti gba ibi to gba waye pada sọhun-un, oogun ale to lo lati ba ololufẹ rẹ sun lo yiwọ

Adewale Adeoye Owo ti ada mọ ti i ka a leyin ti ṣe bẹẹ ka ọmọkunrin…

O ma ṣe o, wọn si pa ọmọ Naijiria to n kẹkọọ niluu oyinbo yii nipa oro

Adewale Adeoye Titi di akoko taa n ko iroyin yii jọ, inu ọfọ ati ironu nla gbaa ni ẹbi, ara ati…

Tinubu kọ lẹta si Funkẹ Akindele, eyi lohun to wa ninu rẹ

Adewale Adeoye Bi ọmọ ẹni ba daa ka sọ, ki i ṣe ka fi ṣ’aya, ọmọ…

Gbese ree o, ijọba gba ọja lori awọn to n taja loju titi l’Ekoo, ni wọn ba bu sẹkun

Faith Adebọla Tẹkun-tomije lawọn ontaja kan ti wọn ṣe kongẹ awọn ẹṣọ amunifọba to n ri…

Wọn ti gbe oku Akeredolu de si Naijiria, awọn mọlẹbi ẹ bara jẹ gidigidi

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Oku Gomina ana nipinlẹ Ondo, Arakunrin Rotimi Akeredolu, ni wọn ti gbe wale…

Lẹyin iku Akeredolu, wahala n bọ ninu ẹgbẹ APC Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Asiko yii kii ṣe eyi to rọrun rara fun igbimọ alaṣẹ ẹgbẹ oṣelu…

Ilẹ n jẹẹyan! Ọlọfana ti wọ kaa ilẹ lọ, awọn eeyan bara jẹ gidigidi  nibi isinku ẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ko si bi eeyan ẹni ṣe le dagba dagba to laye ti tọhun…

Imaamu jade lọ ko wọle mọ, iwaju mọṣalasi lawọn agbebọn pa a si 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Imaamu mọṣalaṣi kan niluu New Jersey, lorileede Amẹrika, Hassan Sharif, ti jade aiwọle…