Awọn agbebọn tun paayan marun-un mi-in ni Mọdakẹkẹ

Jọkẹ Amọri Iroyin to tẹ wa lọwọ ni pe wọn ti tun pa eeyan marun-un mi-in…

Iyawo to gun ọkọ ẹ pa lọdun keje sẹyin gba ominira lọgba ẹwọn

Ọmọbinrin kan, Rahma Hussein, ko ju ọmọ ọdun mẹrindinlogun (16) lọ lọdun 2014 ti wọn fa…

Pẹlu bi mo ṣe ṣatilẹyin fun Arẹgbẹ fun ọdun mẹjọ, ko si idi fun un lati ma ti mi lẹyin-Oyetọla

Jọkẹ Amọri ‘Pẹlu bi mo ṣe siṣẹ sin gomina Ọṣun tẹlẹ, Ọgbẹni Rafiu Arẹgbẹṣọla, fun odidi…

Imọlẹayọ fipa ba obinrin lo pọ ni Ṣagamu, o loun mu’ti yo ni

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Satide, ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu kẹjọ, ni ọwọ ba gende-kunrin yii, Imọlẹayọ Adekọya,…

Tori bo ṣe tu aṣiri awọn eeyan nla to wa ninu ijọba Buhari to n ṣatilẹyin fun Boko Haram, awọn ọtẹlẹmuyẹ n wa Ajagun-fẹyinti Ọlawunmi

Faith Adebọla, Eko  Awọn ọtẹlẹmuyẹ ileeṣẹ ologun ilẹ wa, Defence Intelligence Agency ti kede pe ki…

Ọwọ tẹ tiṣa ti wọn lo n fipa ba ọmọ to bi ninu ara ẹ lo pọ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Olukọ ileewe girama kan, Nelson Akinṣọwọn, lọwọ ti tẹ lori ẹsun fifipa ba…

Ileeṣẹ ọlọpaa ti doola ẹmi akẹkọọ Fasiti KWASU ti wọn ji gbe ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ yii, nileeṣẹ ọlọpaa, ẹka ti ipinlẹ Kwara, fi…

Wọn tun fi diẹ silẹ ninu awọn ọmọleewe Baptist ti wọn ji ko, wọn lawọn n reti owo awọn  to ku

Faith Adebọla Binu obi awọn ọmọleewe kan ṣe n dun, ti wọn n ki ara wọn…

Tirela to ko okuta danu ni marosẹ Eko s’Ibadan, ni baale ile meji ba ku

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Aago meje aarọ ku ogun iṣẹju ni ijamba mọto kan ṣẹlẹ loju ọna…

Laarin wakati mẹrinlelogun, oṣere tiata meji ku tẹle ara wọn

Faith Adebọla, Eko Oriṣiiriṣii ọrọ ibanikẹdun lo n rọjo lasiko yii lagbo awọn oṣere tiata ilẹ…

Ṣoyinka parọwa sijọba Bẹnẹ: Ẹ fi Sunday Igboho lọrun silẹ o, ẹ jẹ ko maa ba irinajo ẹ lọ  

Nibi ipade awọn oniroyin kan to waye ni ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii, ni ogbontarigi…