Awọn agbebọn tun ji ọmọleewe mẹẹẹdogun ko ni Zamfara, wọn yinbọn pa ọlọpaa ati ọlọdẹ meji to n ṣọ wọn

Faith Adebọla Ojumọ ire kọ lo mọ fọpọ awọn obi ati mọlẹbi awọn akẹkọọ kọlẹẹji ẹkọ…

Alaba yoo pẹ lẹwọn o, ọkunrin oniṣowo kan lo lu ni jibiti  l’Afao-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Yoruba bọ wọn ni ọjọ gbogbo ni ti ole, ṣugbọn ọjọ ṣoṣo ni…

O ma ṣe o, aṣofin ipinlẹ Ondo ku lojiji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe ni ibanujẹ dori awọn eeyan ilu Akurẹ  kodo latari iku ọmọ ileegbimọ…

Eyi lohun tawọn alaṣẹ ileewe TASUED sọ lori akẹkọọ wọn to binu para ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nigba ti iroyin iku Oshọkọya Deborah Ayọmikun gbode kan lọjọ kọkanla, oṣu kẹjọ…

Awọn agbebọn ji ọmọ oṣiṣẹ ọfiisi Buhari gbe ni Kaduna

Faith Adebọla Niṣe ni iṣẹ ijinigbe awọn agbebọn tubọ n gogo si i nipinlẹ Kaduna lasiko…

Ajalu buruku leleyii o, ṣọja mọkanlegun ti wọn ṣẹṣẹ wọṣẹ ologun ku ninu ijamba ọkọ

Faith Adebọla Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Jigawa, Lawan Shiisu Adam, ti fidi ẹ mulẹ pe ko…

Ajẹ niyawo mi, bo ṣe n ba mi ja loju oorun lo n ba mi ja loju aye, mi o fẹ ẹ mọ-Fẹmi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Wọn ti pẹ lẹnu ẹjọ naa, kootu yanju ẹ titi, wọn ko ri…

Ayẹyẹ kan ni olukọ KWASU yii n lọọ dari lati Ilọrin to fi ku sinu ijamba ọkọ lọna Eko 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọmowe Ayọtunde Alao lo ti kagbako iku ojiji lọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ…

Ọmọleewe Chibok mi-in tun jajabọ lọwọ awọn Boko Haram, ọmọ meji loun naa ti bi sọhun-un

Faith Adebọla Lẹyin ọsẹ kan ti wọn fa Ruth Poga ati awọn ọmọ meji to ti…

Lẹyin ti awọn ajinigbe gba miliọnu mẹrin, Ayọ Alabi ti wọn ji gbe ni Kwara ti ku 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Onimọ-ẹrọ Ayọ Alabi pẹlu ẹgbọn rẹ ati awọn ati awọn mẹta miiran lawọn…

Nitori Sunday Igboho, ijọba fẹẹ fofin de ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua, wọn fẹẹ kede ẹ bii ẹgbẹ afẹmiṣofo

Faith Adebọla Pẹlu ibi ti ọrọ ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ, ti gbogbo eeyan…