O ma ṣe o, gende-kunrin ko sodo n’llọrin, oku ẹ ni wọn gbe jade

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gende-kunrin ẹni ọdun mejilelogun kan torukọ rẹ n jẹ Sodiq Mustapha, ọmọ agboole…

Kaadi ATM Quadri ha sẹnu ẹrọ, n loṣiṣẹ banki ba dari owo rẹ sakaunti tiẹ n’Ibadan

Jọkẹ Amọri  Oṣiṣẹ banki ilẹ wa kan, Adeyẹmi Tosin, ẹni ọdun mẹrindinlogoji, ti dero ahamọ ọlọpaa…

Lọjọ to yẹ ki kootu gba beeli awọn ọmọ Igboho ladajọ gba oke okun lọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu kẹjọ yii, ni gbogbo eto lati gba…

Igbakeji ọga ọlọpaa Ẹkun kọkanla bẹrẹ iṣẹ

Florence Babaṣọla Ẹkun kọkanla ileeṣẹ ọlọpaa (Zone XI), eleyii ti ibujoko rẹ wa niluu Oṣogbo ti…

Ọladayọ ni kijọba ipinlẹ Ọṣun foun niṣẹ, oun naa fẹẹ ṣe bii baba gidi ninu ile

Florence Babaṣọla Gbogbo awọn ti wọn wọle sinu sẹkiteriati ijọba ipinlẹ Ọṣun to wa ni Abere,…

Pẹlu bi b’awọn Taliban ṣe gbajọba ni Afghanistan, inu ewu nilẹ Afrika wa-Buhari

Faith Adebọla Aarẹ ilẹ wa, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari ti sọ pe bawọn ajagunta Taliban ṣe gbajọba…

Bi nnkan ba n lọ bo ṣe n lọ yii, ọjọ kan la maa ji torileede yii maa dawati– Fani-Kayọde

 Faith Adebọla, Eko  Minisita feto igbokegbodo ọkọ ofurufu nigba kan, Fẹmi Fani-Kayọde, ti bẹnu atẹ lu…

FIDIO: Ẹ GBÀ MÍ LỌ́WỌ́ ÌJỌBA ÈKÓ, MI Ò NÍ ÀRÙN KÒRÓNÀ, WỌN Ò SÌ JẸ́ KÍ N LỌ

Aṣofin Kwara fẹẹ gba ẹbun ironigbara to fun ọmọlẹyin ẹ, o ni ko ṣatilẹyin foun mọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Aṣofin kan nipinlẹ Kwara,  Họnọrebu Razaq Owolabi, to n ṣoju Share/Oke-Ode, ti n…

Orileede Italy lobinrin yii dagbere, aṣe egboogi oloro lo fẹẹ gbe lọ sọhun-un

Faith Adebọla, Eko Bi gbogbo aye ṣe n dagbere irinajo ilẹ okeere fawọn eeyan wọn naa…

Awọn agbebọn tun ji ọmọleewe mẹẹẹdogun ko ni Zamfara, wọn yinbọn pa ọlọpaa ati ọlọdẹ meji to n ṣọ wọn

Faith Adebọla Ojumọ ire kọ lo mọ fọpọ awọn obi ati mọlẹbi awọn akẹkọọ kọlẹẹji ẹkọ…