Awọn mẹta yii ja Tọpẹ Alabi lole owo nla

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Idigunjale lawọn gende mẹta yii, Aanu Ibikunle, Rasheed Bisiriyu ati Adebọwale Dada, yan…

Adajọ sọ awọn baba agbalagba meji satimọle, awọn ọmọde ni wọn fipa ba laṣepọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ti wọn fipa ba ọmọdebinrin kan sun ni tipatipa, kootu to n…

Eyi ni bi iku ojoji ṣe yẹ lori awọn eeyan lasiko ti baaluu kan ja n’Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ yii, ni baaluu kan to jẹ ti Peace airline…

Ọpọ eeyan ko jade dibo ijọba ibilẹ nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko sija, ko si jagidijagan, ṣugbọn ko si awọn oludibo to bẹẹ ju…

Mohammed ṣa ọmọ bibi inu rẹ pa, ladajọ ba ju u sẹwọn ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Magistreeti kan niluu Ilọrin, ti ni ki arakunrin Yahaya Mohammed maa lọọ…

Lẹyin ọdun mẹsan-an, Oyetọla gbọpa aṣẹ fun Ọwaloko Ijẹṣa tuntun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Adegboyega Oyetọla, ti parọwa si Ọwaloko ti Iloko-Ijeṣa tuntun,…

Ọrẹ meji ṣe paṣipaarọ iyawo, wọn lawọn fi pari ija ni

Ba  a ba lowo, a le ya ẹnikeji ẹni, o si le jẹ aṣọ tabi mọto, ṣugbọn…

O ma ṣe o, ibi ti God’stime at’ọrẹ ẹ ti n pẹja lomi ti gbe wọn lọ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe nibanujẹ dori awọn eeyan agbegbe Sir Ọlabanji Akingbulẹ Road, Arigbabọla, niluu Ondo,…

Ibọn onike ni John fẹẹ fi gbowo lọwọ oni-POS n’Ikorodu tọwọ fi tẹ ẹ

Faith Adebọla, Eko Ọwọ palabi ọkunrin ẹni ọdun mẹrindinlogoji kan ti se’gi n’Ikorodu, o ti dero…

Irẹsi ni James fẹẹ lọọ ra to fi sọnu fọdun marundinlaaadọta, oṣu keje yii lo wọle de wẹrẹ

Ko kuku sohun ti ko ṣee ṣe f’Ọlọrun b’asiko ba to lati ṣe e, iyẹn gan-an…

Ibọn onike ni John fẹẹ fi gbowo lọwọ oni-POS n’Ikorodu tọwọ fi tẹ ẹ

Faith Adebọla, Eko Ọwọ palabi ọkunrin ẹni ọdun mẹrindinlogoji kan ti se’gi n’Ikorodu, o ti dero…