Nitori Baba Ijẹṣa, babalawo kan ṣepe fun Iyabọ Ojo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi ẹnikan ba wa to loun mọ ibi ti ọrọ Baba Ijẹṣa yii…

T B Joshua wọ kaa ilẹ lọ, Akeredolu, Sanwo-Olu atawọn nla nla ṣẹyẹ ikẹyin fun un

Faith Adebọla, Eko  Bi ẹsẹ ko ṣe gbero ni gbagede ati ayika ṣọọṣi Synagogue Church of…

Nitori Sunday Igboho, Oluwoo bẹ Buhari, o lo ti kẹkọọ pe Naijiria ko ṣe e pin

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti rawọ ẹbẹ si Aarẹ…

Ipinnu tawọn kan ṣe pe apa Guusu ni aarẹ ti gbọdọ wa lodi sofin- Yahaya Bello

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Kogi, Yahaya Bello, ti sọ pe oun o fara mọ ipinnu tawọn…

Wọn yinbọn pa igbakeji MC Oluọmọ nibi ipolongo ibo APC l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko  Niṣe lọrọ di bo-o-lọ-o-yago nigba ti iro ibọn ṣadeede dun, to si ṣeku…

Sunday Igboho atawọn mẹtala ti wọn mu pe ijọba Buhari lẹjọ s’Abuja

Faith Adebọla Oloye Sunday Adeyẹmọ tawọn eeyan mọ si Sunday Igboho ti pe ijọba apapọ ati…

Gomina Kwara ṣedaro Ẹmir Lafiagi to ku

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrasaq, ti ba mọlẹbi, awọn eeyan ilu Lafiagi ati…

Apo irẹsi, ẹwa, maggi, iyọ ati garawa ororo lawọn to ji ọmọleewe ni Kaduna n beere fun

 Faith Adebọla Ṣe wọn ni bi iya nla ba gbe ni ṣanlẹ, kekere a maa gori…

Awọn agbebọn tun ji eeyan mẹrinla gbe ni Kaduna, wọn paayan mẹrinlelogun ni Adamawa

Faith Adebọla Iduro ko si, ibẹrẹ ko si mọ, fun ọpọ araalu lagbegbe Oke-Ọya ilẹ wa,…

Faith Adebọla, Eko  Ẹni to ba ri ọkunrin ẹni ọdun mẹtalelọgbọn ka, Aminu Al-Amin, nibi to…

Awọn aṣofin Ogun dabaa ẹwọn ọdun mẹta fẹni to ba fẹran jẹ oko oloko

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹwọn ọdun mẹta lai ni owo itanran ninu, gbigbẹsẹ le ẹranko to jẹ’ko…