Awọn ọtẹlẹmuyẹ n wa ọga agba Fasiti Ọyẹ Ekiti, wọn lo n gbowo-oṣu lọna meji

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Bii ere ori itage lọrọ ri ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee,  ọsẹ yii, laarin ọga agba…

Pasitọ ṣeku pa obinrin to ba aajo ọmọ lọ sọdọ rẹ, ladajọ ba ju u sẹwọn gbere l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Ile-ẹjọ giga ilu Ado-Ekiti ti ran Pasitọ Ọlakanye Oni, lẹwọn gbere fun ẹsun iṣeeṣipaayan. Ẹjọ to ran Pasitọ Ọlakanye lẹwọn…

 Awọn Fulani to ji ọba gbe l’Ekiti ti wa lahaamọ

 Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Ile-ẹjọ Majisitreeti kan to fi ilu Ado-Ekiti ṣe ibujokoo ti paṣẹ pe kawọn Fulani meji kan, Abdulameen Lawal; ẹni aadọta ọdun ati…

Nitori iwọde ‘Orileede Odua’ tawọn kan fẹẹ ṣe ni Satide, Odumosu da ọpọlọpọ ọlọpaa sita l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, CP Hakeem Odumosu, tun ti jade laago ikilọ pe…

Ifẹtẹdo, nipinlẹ Ọṣun, ni Ọtẹdọla n ko ọpọlọpọ ori eeyan ti wọn ba lọwọ rẹ lọ tọwọ fi tẹ ẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn marun-un ni wọn ti wa lakolo ọlọpaa ipinlẹ Ondo lori ẹsun tita…

Nitori oye ọba awọn Hausa to fẹẹ fi jẹ niluu naa, Ọba Jẹbba wọ Emir Ilọrin lọ sile-ẹjọ 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọba ilu Jẹbba, nijọba ibilẹ Moro, nipinlẹ Kwara, Abdulkadir Adebara, ati Serikin Hausawa…

Adajọ lawọn ọmọ ‘Yahoo’ toun da lẹbi le waa ṣẹwọn wọn lẹyin ti wọn ba ṣetan nileewe giga ti wọn wa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Nitori ẹsun jibiti lori ẹrọ ayelujara, ile-ẹjọ giga kan to wa niluu Ilọrin,…

 Awọn aafaa yii to tọọnu lori iyawo oniyawo, wọn ni oro to gbọdọ ṣe ko too dọmọ ẹgbẹ awọn ni

Awọn aafaa mẹta yii, Tukur Danazumi; ẹni ọdun mọkandinlogun, Abubakar Yahuza; ẹni ogun ọdun, ati Rufai…

Iwọde ‘Oodua Nation’ yoo waye niluu Eko ni Satide-Sunday Igboho

Faith Adebọla Ajigbagbara ọmọ Yoruba tawọn ọtẹlẹmuyẹ lọ sile rẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, Oloye Sunday…

Awa la paayan meji nile Sunday Igboho – DSS

Ileeṣẹ ọtẹlẹmuyẹ ilẹ wa ti jade sita, wọn si ti jẹwọ pe loootọ loootọ, awọn lawọn…

Ọlọpaa ti mu Imaamu ijọ Kamọrudeen ati atọkun eegun Eṣuleke to koju ija sira wọn l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla Ikọ awọn ọlọpaa ti wọn n ṣewadii wahala to bẹ silẹ laarin awọn ọmọ…