Ẹ fi Sunday Igboho silẹ, ẹ ṣewadii ọmọ tawọn ọlọpaa pa l’Ọjọta- Iyawo Odumakin

Faith Adebọla, Eko Dokita Joe Okei-Odumakin, iyawo gbajugbaja ajafẹtọọ nni, Oloogbe Yinka Odumakin, ti bẹnu atẹ…

Ile-ẹjọ kọ lati gba beeli awọn afurasi mẹjọ ti wọn pa akẹkọọ Fasiti Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ giga ipinlẹ Kwara ti kọ lati gba beeli awọn afurasi mẹjọ ti…

Ijọba dawọ yiyan ọba tuntun duro niluu Awo-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii nijọba ipinlẹ Ekiti paṣẹ pe ki awọn…

Nitori fiimu ‘Ọkọ Iyabọ’ to ṣe, TAMPAN ranṣẹ pe Yọmi Fabiyi

Faith Adebọla, Eko Yoruba bọ, wọn ni ko yẹ keeyan gbẹ koto ọta rẹ jin ju,…

Nitori to lu jibiti lori ẹrọ ayelujara, adajọ sọ Gideon sẹwọn ọgbọn ọjọ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Monde, ọṣẹ yii, nile-ẹjọ giga ipinlẹ Kwara  Ọkẹ Gedeon, ẹni ogun…

Awọn ajinigbe to ji agbẹ mẹrin n’Ikosun-Ekiti n beere aadọta miliọnu naira

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Awọn ajinigbe to ji awọn agbẹ mẹrin gbe ni Ikosun-Ekiti ti beere aadọta…

Awọn agbebọn tun ti ji awọn arinrin-ajo gbe l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Awọn ọlọpaa, ọlọdẹ atawọn ajijagbara Kiriji ti bẹrẹ wiwa awọn arinrin-ajo ti awọn agbebọn…

Nitori ọrọ Baba Ijẹṣa to fi ṣe fiimu, awọn oṣere binu si Yọmi Fabiyi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Inu buruku lo n bi awọn oṣere tiata Yoruba kan si akẹgbẹ wọn,Yọmi…

Jubril fẹṣẹ yọ eyin Mark l’Ọta, lo ba loun ko jẹbi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọ Ẹti to kọja yii ni Abioye Jubril, ẹni ọdun mẹtalelọgbọn, foju ba…

Lati asiko yii lọ, ọlọpaa ijọba apapọ ko gbọdọ mu ẹni ti wọn n wa nipinlẹ kan lai gbaṣẹ lọwọ gomina ibẹ-Awọn gomina Guusu

 Faith Adebọla, Eko   Awọn gomina mẹtadinlogun lati agbegbe Guusu ilẹ wa ti ṣepade nla kan niluu…

 Ẹyin awakọ, e yee rin ọna Idiroko lẹyin aago mẹfa irọlẹ o – FRSC

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta FRSC ẹka Idiroko, nipinlẹ Ogun, ti ṣekilọ fawọn awakọ to n gba oju…