Ọwọ tẹ baale ile mẹrin to ji ẹrọ amunawa MTN n’ Ijoko-Ọta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣinkun lawọn ọlọpaa mu awọn baale ile mẹrin yii, Clement Idenyi; ẹni ọdun…

Ijọba Ogun bẹrẹ abẹrẹ ajẹsara to n dena arun digbolugi lara aja

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Ẹgbẹrun mẹfa abẹrẹ ajẹsara to le dena arun digbolugi lara awọn aja kaakiri…

”Ẹẹmẹta ọtọọtọ ni Ọlọrun fi han mi pe TB Joshua maa ku, mo si sọ fun un”

Oludari ijọ kan ti wọn n pe ni Champions Royal Assembly, to wa niluu Abuja, Wolii…

Tirela tẹ awọn obinrin meji pa nibi ti wọn ti n kiri ọja ni marosẹ Eko s’Ibadan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Gbinrin-gbinrin ni agbegbe Lotto, loju ọna marosẹ Eko s’Ibadan, kan lọjọ Ẹti, Furaidee …

Ijọba Kwara fawọn to padanu dukia wọn ninu ijamba ina lọja Oro ni miliọnu mẹta 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara ti mu ileri rẹ ṣẹ pẹlu fun awọn to padanu…

Ajinigbe ku iku ojiji l’Ọdẹda, lẹni ti wọn ji gbe ba dominira

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọsan gangan laago mejila ọjọ Ẹti, ọjọ kẹrin, ọsu kẹfa yii, ni DPO…

Inu ọgba ileewe ti wọn ti n ṣedanwo lọwọ lawọn eleyii ti lọọ jale l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ahamọ ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ lawọn afurasi adigunjale meji kan, Tunji Lawal ati Ikechukwu Oguawai,…

Lẹyin tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ja oni POS lole l’Oṣogbo, wọn tun pa ọkunrin kan

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti…

Ẹṣọ Amọtẹkun gbọdọ ṣiṣẹ pọ lati koju ipenija eto aabo nilẹ Yoruba- Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ni awọn ti paṣẹ fawọn ẹsọ Amọtẹkun ni…

Iwadii bẹrẹ lori ṣọja to gun ọtẹlẹmuyẹ pa l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Iwadii ti bẹrẹ lori iku ojiji to pa oṣiṣẹ ọtẹlẹmuyẹ (DSS) kan latọwọ…

Ayederu owo ni Kelechi ati ọrẹ ẹ na ni Kwara tọwọ fi tẹ wọn

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ẹsọ alaabo (NSCDC) ẹka ti Patigi, nipinlẹ Kwara, ti nawọ gan Nicholas Kelechi…