‘Ẹ maa too dohun igbagbe ninu itan Yoruba pẹlu bẹ ẹ ṣe kọyin sohun tawọn eeyan yin fẹ’

Adefunke Adebiyi   Ọkan ninu awọn ẹgbẹ to n pe fun idasilẹ Orilẹ-ede Yoruba ni ẹgbẹ kan…

Akẹkọọ FUNAAB ti wọn ji gbe ti gba itusilẹ

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta  Nathaniel Toyinbo Ọlayinka, akẹkọọ ileewe imọ ọgbin, FUNAAB, ti wọn ji gbe labule Itoko,…

Oyetọla, Owoẹyẹ gboṣuba fun Arẹgbẹṣọla layaajọ ọjọọbi rẹ

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti ki ẹni to gbaṣẹ lọwọ rẹ,…

Ipade tawọn Tinubu ṣe l’Ekoo yẹn, wọn fakoko ṣofo lasan ni – Fani-Kayọde

Faith Adebọla, Eko Minisita fun igbokegbodo ọkọ ofurufu ilẹ wa nigba kan, Oloye Fẹmi Fani-Kayọde, ti…

Kansilọ atawọn alaga kansu tuntun ipinlẹ Ọyọ bẹrẹ iṣẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn kansilọ atawọn alaga kansu tawọn araalu ṣẹṣẹ dibo yan ninu idibo ijọba…

Ileeṣẹ ti Abdulrahman ti n ṣiṣẹ lo ja lole tọwọ fi tẹ ẹ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọkunrin ẹni ọdun mejilelogoji kan, Abdulrahman  Kadri, to ja ileeṣẹ to n ti…

Ipinlẹ Ogun at’Eko tọwọ bọwe adehun lori ọrọ-aje, nnkan amayederun, eto aabo atawọn mi-in

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ki ibaṣepọ to gun rege, ti yoo si mu ọrọ aje, nnkan amayedẹrun,…

Buhari ni bawọn gomina ṣe fofin de dida maaluu nigboro, ifiya jẹ Fulani ni

Faith Adebọla Aarẹ orileede wa, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari, ti fajuro si bawọn gomina iha Guusu ilẹ…

Wọn fa aworan ti wọn fi ki Aregbeṣọla ku oriire ọjọọbi ya l’Oṣogbo

Ko jọ pe wahala ‘iwọ lo ju mi, emi o ju ọ’ to n fojoojumọ waye…

Tirela to kun fun fulawa lawọn eleyii digun gba ni Ṣagamu, Eko lọwọ ti tẹ wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọ kẹrindinlogun, oṣu kẹrin, ọdun 2021, lawọn ọkunrin mẹrin yii da tirela kan…

Awọn agbebọn ji iyawo olori ọdọ APC ipinlẹ Ọyọ gbe niṣeju ọkọ ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Kọlukọlu ijinigbe to n ṣẹlẹ lemọlemọ nipinlẹ Ọyọ lẹnu ọjọ mẹta yii ti…