Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kootu Majisireeti to n jokoo l’Abẹokuta ti paṣẹ pe ki wọn ju ọkunrin…
Ṣoworẹ atawọn ọdọ tun ṣewọde l’Abuja, wọn ni dandan ni ki Buhari lọ
Faith Adebọla Ọjọ Aje ti kaluku n gba ọna iṣẹ aje lọ lọjọ Mọnde, ṣugbọn niṣe…
Ẹ wo Adeṣina to fipa ba iya ọgọta ọdun lo pọ n’Idanyin
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Adeṣina Adebọwale lorukọ ọkunrin yii, ẹni ogoji ọdun ni. Ọjọ Sannde ọsẹ yii…
Ko sẹni to le da wa duro, iwọde Yoruba Nation maa waye l’Ekoo loṣu keje
Faith Adebọla Bi ko ba si ayipada, ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹta, oṣu keje, to n…
Abayọmi to n ta oogun oloro fawọn akẹkọọ FUNAAB bọ sọwọ NDLEA l’Abẹokuta
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọkunrin kan, Abayọmi Popoọla, to n gbe niluu Eko, ṣugbọn to maa n…
Abimbọla at’ọrẹkunrin ẹ lọọ sa pamọ I’Ekiti, ni wọn ba ranṣẹ sile pe wọn ji awọn gbe
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Fun dida ọgbọn alumọkọrọyi lati gba owo lọwọ awọn obi wọn, awọn ololufẹ…
Awọn agbebọn kọ lu teṣan ọlọpaa ni Benue, wọn ba pa mẹrinla ninu wọn
Faith Adebọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Benue ti fidi ẹ mulẹ pe ohun ti awọn agbebọn kan…
Nibi ti kọsitọọmu at’onifayawọ ti n bara wọn ja ni wọn ti yinbọn pa ọmọọlewe kan ni Badagry
Faith Adebọla, Eko Ibanujẹ ati ọfọ nla ti ṣẹlẹ sawọn mọlẹbi akẹkọọ ọmọ ọdun mejidinlogun kan,…
Tọpẹ Alabi dupẹ lọwọ gbogbo awọn ololufẹ ẹ fun aduroti wọn
Faith Adebọla Latari awuyewuye to waye lọsẹ to kọja lori ọrọ abuku to sọ nipa orin…
Ohun kan ṣoṣo ti mo fẹ ni kijọba gbẹsan lara awọn to ṣeku pa ọmọ mi-Iya Ramon
Faith Adebọla Alaaja Salimọt Azeez, iya ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlogoji kan, Ramon Azeez, ti wọn fibọn…
Ajagungbalẹ mẹta ko sọwọ ọlọpaa l’Odogbolu
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi awọn ọkunrin yii ṣe ti wa ni ahamọ awọn ọlọpaa, lẹka itọpinpin,…